Ìṣẹ́yún

Ìṣẹ́yún tabi oyún ṣíṣẹ́ (Ìṣẹ́yún, ṣíṣẹ́ oyún) ni fifi opin si Oyún nipa yiyọ tabi fifi tipatipa mu oyún-inu tabi ọmọ inu-oyín kuro ni ile ọmọ ṣaaju ki o to le yè fun ara rẹ.

Oyún ṣíṣẹ́ kan le dede waye lojiji, ni eyi ti o jẹ wipe a npe ni Oyún ti o bajẹ. A tun le mọọmọ ṣe okunfa rẹ, ni eyi ti a mọ si oyún ṣíṣẹ́ ti a ṣe okunfa rẹ. Ọrọ naa ti a npe ni oyún ṣíṣẹ́ ni ọpọlọpọ igba duro fun oyún ṣíṣẹ́ ti a ṣe okunfa rẹ ti oyún eniyan. Ilana miiran lẹyin ti oyún-inu ti le da duro ki o si yè fun ra rẹ ni a mọ si "fifi òpin si oyún ti o ti pẹ́" labẹ ìṣègùn oyinbo.

Ìṣẹ́yún
Ìṣẹ́yúnA woman receiving pennyroyal, a common medieval abortifacient. From Herbarium by Pseudo-Apuleius. 13th-century manuscript.
Ìṣẹ́yúnA woman receiving pennyroyal, a common medieval abortifacient. From Herbarium by Pseudo-Apuleius. 13th-century manuscript.
A woman receiving pennyroyal, a common medieval abortifacient. From Herbarium by Pseudo-Apuleius. 13th-century manuscript.
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta
ICD/CIM-10O04. O04.
ICD/CIM-9779.6 779.6
DiseasesDB4153
MedlinePlus002912

Awọn ọna ati ààbò

Ìṣègùn igbalode nlo awọn oogun tabi awọn iṣẹ-abẹ fun oyún ṣíṣẹ́ ti a mọọmọ ṣe okunfa rẹ. Awọn oogun mejeeji naa mifepristone ati prostaglandin jẹ eyiti o munadoko bíi iṣẹ-abẹ laarin oṣu mẹta àkọ́kọ́. Nigbati lilo awọn oogun oyinbo le munadoko ni oṣu mẹta èkejì, awọn ọna iṣẹ-abẹ jọ mọ eyiti ewu rẹ kéré nipa awọn iṣẹlẹ atunbọtan. Ìfètò s’ọmọ bíbí, ati pẹlu oogun naa ati awọn ohun-elo ìfètò s’ọmọ bíbí ti a nfi s’ójú-ara ni a le bẹrẹ si lo ni kété ti a ba ṣe oyún kan. Oyún ṣíṣẹ́ ni awọn orilẹ-èdè to ti dagbasoke ni ìtàn eyiti lara awọn ilana ti o ni idaabobo julọ ni ìṣègùn oyinbo ọlọjọ pipẹ nigbati a ba gba a láàyè labẹ ofin agbegbe. Awọn oyún ṣíṣẹ́ ti kò ba díjú kìí fa ailera ọpọlọ tabi awọn iṣoro ti a le f’ojuri. The Àjọ Ilera L’agbaye gba nimọran pe ki irú ipele oyún ṣíṣẹ́ labẹ ofin eyiti o ni ààbò ki o wa fun gbogbo obinrin l’agbaye. Oyún ṣíṣẹ́ ti kò ní ààbò, ni idakeji, maa nfa bíi 47,000 ikú aláboyúns ati miliọnu marun (5) igbani si ile-iwosan l’ọdun kan l’agbaye.

Ìtàn nipa àjàkále àrùn

O to miliọnu mẹrinlelọgọta (44) oyún ṣíṣẹ́ ti o nwaye l’ọdun kan l’agbaye, ti diẹ si eyi jẹ eyiti a nṣe lai si ààbò. Diẹ ni iye oyún ṣíṣẹ́ fi yatọ laarin ọdun 2003 ati 2008, lẹyin ti o ti fi ọpọlọpọ ọdun dinku nitori bi rírí ààyè si ẹ̀kọ́ nipa fifi ètò s’ọmọ bibi ati dida ọmọ bibi duro ṣe gberu. Títí di 2008, ida ogoji obinrin l’agbaye ti ni ààyè si oyún ṣíṣẹ́ ti a mọọmọ ṣe okunfa rẹ labẹ ofin "lai si idiwọ fun ohun ti o fàá". Ṣugbọn o ni gbèdéke ibi ti oyún le pẹ́ dé ti a fi le ṣẹ́ ẹ.

Ìtàn, àwùjọ ati àṣà

Oyún ṣíṣẹ́ ni ìtàn eyiti o pé ìtàn. A ti ṣe e nipasẹ oriṣiriṣi ọna, ti o ni ninu awọn egbòògi, lilo ohun-elo ti o mú, ibanilọkanjẹ ti a le f’ojuri, ati awọn miiran awọn ọna ibilẹ́ lati igba lailai. Awọn awọn ofin ti o rọ̀mọ́ oyún ṣíṣẹ́ , ni bi o ti ṣe wọ́pọ̀ lati ṣe e tó, ati awọn ipo àṣà ati ti ẹ̀sìn yàtọ̀ si ara wọn gan-an kaakiri agbaye. Ni abẹ awọn iṣẹlẹ kan ni pàtó, oyún ṣíṣẹ́ tọ̀nà labẹ ofin, bíi ibalopọ laarin mọlẹbi, ifipabanilopọ, awọn iṣoro kan pẹlu oyún-inu, awọn nnkan ti o niiṣe pẹlu ọrọ-ajé tabi ewu nipa ilera iya. Ni ọpọlọpọ ibi l’agbaye ariyanjiyan nwa awuyewuye l’awujọ lori bi o ṣe tọ́ sí, ṣíṣẹ̀tọ́, ati awọn ọrọ labẹ ofin lori oyún ṣíṣẹ́. Awọn ti o lodi si oyún ṣíṣẹ́ maa nsọ wipe ọmọ-inu tabi oyún-inu jẹ eniyan ti o si ni ẹ̀tọ́ si ìyè ti wọn si nfi oyún ṣíṣẹ́ wé ìpànìyàn. Awọn ti o faramọ awọn ẹ̀tọ́ oyún ṣíṣẹ́ ntẹnumọ ẹ̀tọ́ obinrin lati pinnu ohun ti o niiṣe pẹlu ra rẹ̀ ti wọn si tun ntẹnumọ awọn ẹ̀tọ́ gẹgẹ bi eniyan l’apapọ.

Àwọn ìtọ́kasí


Itokasi

Tags:

Ìṣẹ́yún Awọn ọna ati ààbòÌṣẹ́yún Ìtàn nipa àjàkále àrùnÌṣẹ́yún Ìtàn, àwùjọ ati àṣàÌṣẹ́yún Àwọn ìtọ́kasíÌṣẹ́yún ItokasiÌṣẹ́yúnIlé-ọmọOyún

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ẸranISO 31-10ISO 5776Àsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáEre idarayaISO 19092-2GánàKòréà GúúsùISO 31-2Kikan Jesu mo igi agbelebuBẹ́ljíọ̀mÈdè Ìṣèlànà Kọ̀mpútàISO 3166-3Èdè Java.mwPaul BiyaISO 22000.nl2022ISO 19011Maya AngelouISO 31-9Vladimir PutinÀwọn GríìkìPOSIXISO 5964ISO 10303-28Catherine Zeta-JonesISO/IEC 8859-12Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìISO 7001.fjISO 9660CherUnified Modeling LanguagePọ́rtúgàlÀṣàKopernisiomuỌ̀rọ̀ayéijọ́un.scOyunLagos State Ferry Services CorporationOrílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin ÁfríkàKontagora.gtGregor MendelISO 31000ISO 4031.suKọ̀mpútàLítíréṣọ̀Edward Adelbert DoisyInternational Organization for StandardizationJPEG XRRamsey NouahISO 9984ISO 2788ISO 14644-4918 IthaComputer Graphics MetafileỌkùnrinTony ElumeluISO 31-6MaxiCodeX3DSheraton Lagos Hotel🡆 More