Ìṣírò

Isiro

Ìṣírò
Tábìlì ìsirò

Awoyemi, Jolaoluwa

AWÓYẸMÍ JỌLÁOLÚWA

ÌṢIRÒ

Àwọn Yorùbá ní ọ̀nà tí wọn ń gbà ṣe ìsirọ̀, bẹ́ẹ̀ ní àti ọmọkékeré ní àwọn Yorùbá ti ń kọ́ ọmọ wọn ni ìṣirò ní ṣíṣe. Wọn yóò ni kí ó máa fi ení, èjì kọrin, ṣere bíi

Ení bí ení ni ọmọde ńkawó

Èjì bí èjì ni àgbàlà ń tayò

Ẹ̀ta bi ẹta ẹ jẹ́ ka tárawa lọ́rẹ

Ayò tí ta náà tún jẹ́ ọ̀nà tí àwọn Yorùbá fi máa ń kọ ìṣirò Yorùbá ni àwọn ọ̀nà tí wọ́n fi ń ṣe ìsirò wọn fún àpẹẹrẹ “lé”, “dín”, “àádọ́”, “ẹ̀ẹ́dẹ́”, - jẹ́ àwọn ọ̀nà fún ìfilé àti ìyokúrò ìṣirò wọn.

Apẹẹrẹ ìṣirò Yorùbá

1-óókan

10-ẹ̀wá

20-ogún

21-Ọ̀kàn lè lógún (20+1 = ọ̀kan lé ni ogún)

26-ẹ̀rìndínlọ́gbọ̀n (30-4 = Ọgbọ̀n dín mẹ́rin)

30-Ọgbọ̀n

40-Ogójì (20x2 = Ogún méjì)

60-Ọgọ́ta (20x3 ogún mẹ́ta)

100-Ọgọ́rùn-ún (20x5) = Ogún lọ́nà márùn-ún)

120-Ọgọ́fà (20x6 = Ogún lọ́nà mẹ́fà)

50-àádọ́ta (20 x3 = 10, ẹ́wàá dín nínú ogún mẹ́ta)

200-Igba

240-Òjìlélúgba (40+200; Òjì = 40)

300-Ọ̀ọ́dúnrún

340-Ọ̀tàdín nírinwó (400-60 = ọ̀tà = 60 lọ́gbọ́ta)

800-Ẹgbẹ̀rin (igba mẹrin 200x4)

900-Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún (1000-100 = Ọgọ́rùn-ún dín ni Ẹgbẹ̀rún

1000-Ẹgbẹ̀rún

1600-Ẹgbẹ̀jọ (200x8 = igba méjọ

2000-Ẹgbẹ̀wàa (ẹgbàá) (200x10 – igba ní ọ̀nà mẹ́wàá)

4000-Ẹgbàajì (2000x2)

6000-Ẹgbàata (2000x3)

7000-Ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin (8000-100 = Ọgọ́rùn-ún, dín nínú Ẹgbàárin (800)

10, 000 -Ẹgbàarùn-ún (Ẹgbẹ̀rùn-ún àádọ́ta ẹgbẹ̀rùn-ún - àádọ́ta ọ̀kẹ́).



Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Tim Berners-LeeThe Village HeadmasterOmikíkanIfáOwóníná13 AprilErékùṣù ÀjíndeLinda IkejiHirohitoIstanbulÀwọn Ùsbẹ̀kÀkúrẹ́DiocletianAndromeda GalaxyÌwé9 FebruaryNew ZealandMàláwìDubai.vn24 DecemberẸ̀yà ara ìfọ̀Dẹ́nmárkìGuayaquilKàlẹ́ndà GregorySheik Muyideen Àjàní BelloGhánàSony18 DecemberNàìjíríàÌgbà Òṣèlú Kẹta FránsìWKìnìúnỌjọ́bọ̀Ẹ̀sìn IslamWikipediaÈdè FaranséPlatoEuropeÌkéde Akáríayé fún àwọn Ẹ̀tọ́ ỌmọnìyànBàbàÌhìnrere JòhánùLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Ìwọ̀orùn Jẹ́mánìFile Transfer ProtocolỌmọÌlu Frankfọrtì22 MarchISO 8601Ẹlẹ́sìn KrístìEwéAngolaEosentomidaeÀjọ àwọn Orílẹ̀-èdèAnkaraKẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilàShepseskafIlẹ̀ọbalúayé Rómù ApáìlàoòrùnItan Ijapa ati AjaLuther VandrossÌbàdàn2021Ernest Hemingway12 May27 December10 August🡆 More