Èdè Afaaru

Afaaru

Avar

Ọmọ ẹgbẹ́ àwọn èdè tí wọ́n ń pè ní Dagestanian ni eléyìí. Dangestanian yìí tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ fún àwọn èdè tí wọ́n ń pè ní Caucasian. Àwọn tí ó ń sọ Caucasian yìí tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹ̀tà ní Caucasus ní pàtàkì ní ìpínlẹ̀ Dagestan ní Rọ́síà àti Azerbaijan. Àkọtọ́ Cyrillic ni wọ́n fi kọ ọ́ sílẹ̀. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀yà ní àdúgbò yìí ni wọ́n ń lò wọ́n gẹ́gẹ́ bí èdè ìṣèjọba. Àwọn Andi àti Dido náà wà lára àwọn ẹ̀yà tí ó ń lò wọ́n.


Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Mandraka DamOmiYinka AjayiNàìjíríàJoe Biden27 JuneErnest MonisIbadan Peoples Party (IPP)Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Ẹ́gíptìRwanda25 AprilEhoroRodrigo Borja CevallosISO 2014NATOTariq al-Hashimi.uyÌtàn ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàlJennie KimFlorent SerraSylvester MaduJapanMonicazationEre idarayaOwe YorubaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáCreative CommonsÈkánnáÁntígúàOlógbòMandy PatinkinOvie Omo-AgegeAtlantaIndonésíàLionel JospinOdò DánúbìApá MonoÌtúká onítítànyindinÀwọn èdè Índíà-EuropeÀsìá ilẹ̀ Bẹ̀rmúdàPorto-NovoMọ́rísìMoky MakuraKentuckyAndrew JacksonEmperor Junna202412766 PaschenCarl LinnaeusPonun StelinMenachem BeginÌdílé AugustaNgozi NwosuIlẹ̀ọba Aṣọ̀kan Nẹ́dálándì10 August2 DecemberSpéìnSanusi Lamido SanusiẸ̀bùn Nobel nínú Ìṣiṣẹ́ògùnÒrìṣà EgúngúnṢE (Idanilaraya)Apágúúsù EuropeIlẹ̀ọba Aṣọ̀kan13 OctoberISO 9🡆 More