Èdè Áfríkáánì

Àdàkọ:Wiktionary Èdè ìwọ̀ oòrùn Jámìnì (a West Germany language) tí ó wáyé láti ara Dọ́ọ̀jì (Dutuh) ni eléyìí tí wọ́n ń sọ ní Gúsù Aáfíríkà.

Àwọn tí ó ń sọ ọ́ tó míhíọ̀nù mẹ́fà. Wọ́n ń sọ ọ́ ní Nàmíbíà, màláwì, Zambia àti Zimbabwe. Àwọn kan tí ó sì ti ṣe àtìpó lọ sí ilẹ̀ Australia àti Canada náà ń sọ èdè náà. Wọ́n tún máa ń pa èdè yìí ni kéépú Dọọ̀jì (lapa Dutch). Èdè àwọn tí ó wá tẹ ilẹ̀ Gúsù Aáfíríkà dó ní ṣẹ́ńtúrì kẹtàdínlógún (17th century) ni ṣùgbọ́n ó ti wá yàtọ̀ sí èdè Dọ́ọ̀jì (Dutch) ti ilẹ̀ Úroòpù (Europe) báyìí nítorí èdè àdúgbò kọ̀ọ̀kan ti ń wọ inú rẹ̀. Èdè yìí ni èdè tí ó lé ní ìdajì àwọn funfun tí ó dó sí Gúsù Aáfíríkà ń sọ. Ìdá àádọ́sà n-án àwọn tí òbí wọn jẹ́ ẹ̀yà méjì ni ó sì ń sọ èdè yìí pẹ̀lú. Láti ọdún 1925 ni wọn ti ń lo èdè yìí pẹ̀lú èdè Gẹ̀ẹ́sì gẹ́gẹ́ bí èdè ìjọba. Èdè yìí tin í lítírésọ̀. Àkọtọ́ Rómáànù ni wọ́n fi ń kọ ọ́.

Afrikaans
Sísọ níGúúsù Áfríkà South Africa
Namibia Namibia
Bòtswánà Botswana
Lèsóthò Lesotho
Swaziland Swaziland
AgbègbèSouthern Africa
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀est. 6.45 million (first language)
6.75 million (second or third language)
12 to 16 million (basic language knowledge) estimation October 2007[citation needed].
Èdè ìbátan
Indo-European
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Èdè oníbiṣẹ́ níGúúsù ÁfríkàSouth Africa
Àkóso lọ́wọ́Die Taalkommissie
(The Language Commission of the South African Academy for Science and Arts)
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1af
ISO 639-2afr
ISO 639-3afr


Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ISO 3166-2Àsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáISO/IEC 80000LitasEre idarayaGhana.gwÈtò ajéPragueGbISO 31-428 AprilBrigitte BardotIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanISO/IEC 38500VHilary SwankOAlbert LutuliIsaac Babalola AkinyeleAkira Suzuki (chemist)ISO 14031Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Christiane Chabi-KaoISO 3166WISO 11898Fidio ereJean-Jacques RousseauISO 10487Rita HayworthISO 3166-3NebraskaISO 4ISO 639-5Ìran YorùbáÀfin BeaumontPópù Felix 3kISO 639-218572 Rocher2022ṢàngóISO 11783Èdè ÁrámáìkìISO 3977Akademio de EsperantoISO 9660.gbISO 843PDF/AISO 13490ISO/IEC 27000ÌbàdànKọ́nsónántì èdè YorùbáXÈdè EfeDj snakeISO 15926Fuel oilQueen's Counsel22 February3169 Ostro.hrISO 14000Èdè Ìṣèlànà Kọ̀mpútàTallinnISO/IEC 8859-1ISO/IEC 8820-5ISO 1000.jeJPEG XR🡆 More