Àlgéríà

2°22′23″E / 29.5734571°N 2.3730469°E / 29.5734571; 2.3730469

Àlgéríà (Arabiki: الجزائر, al-Gazā’ir), fun onibise Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú àwọn Ènìyàn ilẹ̀ Àlgéríà, je orile-ede ni Àríwá Áfríkà. Ile re ni ti orile-ede ti o tobijulo ni Okun Mediterraneani, ekeji totobijulo ni orile Áfríkà leyin Sudan, ati ikokanla totobijulo lagbaye.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú àwọn Ènìyàn ilẹ̀ Àlgéríà
People's Democratic Republic of Algeria

الجمهورية الجزائرية الديمقراطية الشعبية (Arabic)
République algérienne démocratique et populaire  (Faransé)
Emblem ilẹ̀ Àlgéríà
Motto: بالشّعب وللشّعب
("By the people and for the people")
Orin ìyìn: Kassaman
(English: "We Pledge")
Ibùdó ilẹ̀  Àlgéríà  (dark green)
Ibùdó ilẹ̀  Àlgéríà  (dark green)
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Algiers
36°42′N 3°13′E / 36.700°N 3.217°E / 36.700; 3.217
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaArabic • Berber
Other languagesFrench (administration, business and education)
Algerian Arabic (Darja) (lingua franca)
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
  • Arab-Berber 99%
  • 1% Others
Ẹ̀sìn
  • 99% Islam (official)
  • 1% other (inc. Christians and Jews)
Orúkọ aráàlúAlgerian
ÌjọbaUnitary semi-presidential constitutional republic
• President
Abdelmadjid Tebboune
• Prime Minister
Nadir Larbaoui
• Council Speaker
Salah Goudjil
• Assembly Speaker
Slimane Chenine
AṣòfinParliament
• Ilé Aṣòfin Àgbà
Council of the Nation
• Ilé Aṣòfin Kéreré
People's National Assembly
Formation
• Zayyanid dynasty
1235
• Al Jazâ'ir
1515
• French Occupation
5 July 1830
• Independence from France
3 July 1962
• Recognised
5 July 1962
• Current constitution
10 September 1963
Ìtóbi
• Total
2,381,741 km2 (919,595 sq mi) (10th)
• Omi (%)
1.1
Alábùgbé
• 2020 estimate
43,600,000 (32nd)
• Ìdìmọ́ra
17.7/km2 (45.8/sq mi) (168)
GDP (PPP)2019 estimate
• Total
$684.649 billion (35th)
• Per capita
$15,765 (82nd)
GDP (nominal)2019 estimate
• Total
$180.687 billion (53rd)
• Per capita
$4,229 (109th)
Gini (2011)27.6
low
HDI (2018) 0.759
high · 82nd
OwónínáDinar (DZD)
Ibi àkókòUTC+1 (CET)
Irú ọjọ́ọdúndd/mm/yyyy
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù+213
ISO 3166 codeDZ
Internet TLD.dz
الجزائر.

Àlgéríà i bode ni ariwailaorun mo pelu Tùnísíà, ni ilaorun pelu Libya, ni iwoorun pelu Moroko, ni guusuiwoorun pelu Apaiwoorun Sahara, Mauritania, ati Mali, ni guusuilaorun pelu Niger, ati ni ariwa pelu Okun Mediterraneani Sea. Titobi re fe je 2,400,000 square kilometres (930,000 sq mi), be si ni iye awon eniyan re je 35,700,000 ni January 2010. The capital of Algeria is Algiers.

Àlgéríà je omo egbe Iparapo awon Orile-ede, Isokan Afrika, ati OPEC. Bakanna o tun kopa ninu dida ikoenu owo Isokan Maghreb.



Akiyesi

Itokasi


Tags:

Geographic coordinate system

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdèÈdè JavaLiberiaJack LemmonPornhubÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàAbdullahi Ibrahim (ológun)ÈdèKọ̀mpútàOctave MirbeauUniform Resource LocatorOlógbòOṣù Kínní 7Mẹ́ksíkòXVladimir NabokovOṣù KẹtaÒfinWikisourceÀdírẹ́ẹ̀sì IP(213893) 2003 TN2Àṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáỌ̀rànmíyànÌpínlẹ̀ ÈkóOrílẹ̀ èdè AmericaSwídìnÌbálòpọ̀Ẹ̀sìnOwo siseOSI model1117 ReginitaOlóṣèlú2009Julie ChristieRio de JaneiroẸ̀tọ́-àwòkọGúúsù Georgia àti àwọn Erékùṣù Gúúsù SandwichAlẹksándrọ̀s OlókìkíEthiopiaIkúAustrálíàDoctor BelloBùrúndìOranmiyanÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ÀrokòYunifásítì HarvardMyanmarSalvador AllendeISBNÀgbérò PythagorasHuman Rights FirstJohn Lewis23 JuneWasiu Alabi PasumaWiki🡆 More