Àjọ Àwọn Orílẹ̀-Èdè: Egbé àwọn Ìjoba Orílẹ̀-èdè

Àjọ Ìṣọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè tabi Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè ni soki (ní èdè Geesi: UNO tàbí UN) jẹ́ àgbájọ káríayé ti eto re je lati fa ifowosowopo ninu ofin kakiriaye, abo kakiriaye, idagbasoke eto inawole, ilosiwaju awujo, eto omoniyan ati imudaju alafia lagaye.

OA je didasile ni odun 1945 leyin Ogun Agbaye Keji lati sedipo Apejo awon Orile-ede, lati jawo awon ogun larin awon orile-ede, ki o si pese aye fun ijiroro larin won. O ni opolopo eka akojoegbe kekeke lati le se awon ise wonyi.

Flag of Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè Arabic: منظمة الأمم المتحدة‎ Chinese: 联合国 French: Organisation des Nations unies Russian: Организация Объединённых Наций Spanish: Organización de las Naciones Unidas
Àsìá
Emblem ilẹ̀ Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè Arabic: منظمة الأمم المتحدة‎ Chinese: 联合国 French: Organisation des Nations unies Russian: Организация Объединённых Наций Spanish: Organización de las Naciones Unidas
Emblem
HeadquartersNew York City (international territory)
Official languages
IrúIntergovernmental organization
Ọmọ ẹgbẹ́193 member states
2 observer states
Àwọn olórí
• Secretary‑General
António Guterres
• Deputy Secretary-General
Amina J. Mohammed
• General Assembly President
Tijjani Muhammad-Bande
• Economic and Social Council President
Mona Juul
• Security Council President
Dang Dinh Quy
Ìdásílẹ̀
• UN Charter signed
26 Oṣù Kẹfà 1945; ọdún 78 sẹ́yìn (1945-06-26)
• Charter entered into force
24 Oṣù Kẹ̀wá 1945; ọdún 78 sẹ́yìn (1945-10-24)
Website
UN.org
UN.int
Àjọ Àwọn Orílẹ̀-Èdè: Egbé àwọn Ìjoba Orílẹ̀-èdè
Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè , Geneva
Àjọ Àwọn Orílẹ̀-Èdè: Egbé àwọn Ìjoba Orílẹ̀-èdè


Itokasi

Tags:

Ogun Agbaye KejiOrile-ede

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ISO 3166-2AfricaMauritaniaÀgùàlà9 FebruaryCentral Intelligence Agency67085 OppenheimerEpisteli Jòhánù KejìGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèUlf von EulerKonrad Lorenz6 AugustÒkun ÁrktìkìSony18 NovemberOṣù KẹrinNàìjíríàApágúúsù ÁfríkàFúnmiláyọ̀ Ransome-KútìOdòZanzibarElisabeti KejìKọ́ngrẹ́ẹ̀sì Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàÌbàdànẸ̀yà ara ìfọ̀Fọ́tòyíyà29 FebruaryQÀgbájọ Káríayé fún Ìṣọ̀págunWIlẹ̀ọbalúayé Rómù ApáìlàoòrùnLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀28 July11 MayZincDẹ́nmárkìAgaricocrinusÌbínibíWeb browserApapaỌ̀rọ̀ ìṣeokoẹrúÌhìnrere MárkùDubaiJẹ́ọ́gráfìÌṣúpọ̀ olùgbéỌ̀rọ̀ayéijọ́unÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÀjọ àwọn Orílẹ̀-èdèLeon CooperNebraskaMassÌṣọ̀kan EuropeC++Gani Fawehinmi21 DecemberPatrick Blackett, Baron BlackettTheodor AdornoAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéISO 4217Ọmọ13 DecemberBloemfonteinMedgar EversÒgún LákáayéÒrùn9 MarchFiẹtnámÒkun Mẹditéránì🡆 More