Mathimátíkì: MATIMÁTÌSÌ

Mathematiki tabi Ìmọ̀ Ìsirò jẹ́ èyí t'on jẹ mo nipa ọ̀pọ̀iye (quantity), nipa òpó (structure), nipa iyipada (change) ati nipa ààyè (space).

Idagbasoke imo Isiro wa nipa lilo àfòyemọ̀ọ́ (abstraction) ati Ọgbọ́n ìrọ̀nú, pelu onka, isesiro, wíwọ̀n ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri (shapes) ati bi won se n gbera (motion). E ni awon Onimo Isiro n gbeyewo, ero won ni lati wa aba tuntun, ki won o si fi ootọ́ re mulẹ̀ pelu itumo yekeyeke.

Mathimátíkì: MATIMÁTÌSÌ
Agbègbè tí a tí nko èkó ìsirò ti ile-èkó èkósé owó ti modèle de Galton-Watson.

Mathimátíkì: MATIMÁTÌSÌ

A n lo Imo Isiro ka kiri agbaye ni opolopo ona ninu Imo Sayensi, Imo Ise Ero, Imo Iwosan, ati Imo Oro Okowo. Eyi je mo eko imo isiro to ko ti ni ilo kankan bo tileje pe o se se ki a wa ilo fun ni eyinwa ola.



Àwon Itoka si

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Barbara SokyKàlẹ́ndà GregoryItan Ijapa ati AjaAderemi AdesojiOpeyemi AyeolaÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàEhoroOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìYIṣẹ́ Àgbẹ̀Abdulaziz UsmanÒndó TownJakartaÀwòrán kíkùn3GP àti 3G2Ini Dima-OkojieWikimediaÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáPópù SabinianOlu FalaeÒrùnJack LemmonÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Sean ConneryYul EdochieÀṣà YorùbáMaseruIfá23 JuneInternetGuinea-BissauVladimir NabokovAyéEl SalfadorOwo siseÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáÌpínlẹ̀ ÈkìtìMegawati SukarnoputriNorman ManleyD. O. FagunwaSwídìnKánádàOṣù KejìAtlantaISO 8601Rọ́síàÈdè Rọ́síàÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáWeb browser(211536) 2003 RR11ISBNJohn GurdonSalvador AllendeBaltimoreAfghanístànIPv6Èdè Gẹ̀ẹ́sì🡆 More