Vanuatu ( /ˌvɑːnuːˈɑːtuː/ (ìrànwọ́·info) vah-noo-AH-too or /ˌvænˈwɑːtuː/ van-WAH-too), ni onibise bi orile-ede Olominira ile Vanuatu (Faranse: République de Vanuatu, Bislama: Ripablik blong Vanuatu), je orile-ede erekusu to budo si Guusu Okun Pasifik.
Ile arkipelago, to wa lati ileru, je bi 1,750 kilometres (1,090 mi) si ilaorun apaariwa Ostrelia, 500 kilometres (310 mi) si ariwailaorun Kaledonia Tuntun, iwoorun Fiji, ati guusuilaorun awon Erekusu Solomoni, leba Guinea Tutun.
Republic of Vanuatu Ripablik blong Vanuatu Àdàkọ:Bi icon République de Vanuatu (Faransé) | |
---|---|
Motto: "Long God yumi stanap" (We stand with God) | |
Orin ìyìn: Yumi, Yumi, Yumi ("We, We, We") | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Port Vila |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Bislama, English, French |
Orúkọ aráàlú | Ni-Vanuatu; Vanuatuan |
Ìjọba | Parliamentary republic |
• President | Nikenike Vurobaravu |
• Prime Minister | Charlot Salwai |
Independence | |
• Date | 30 July 1980 |
Ìtóbi | |
• Total | 12,189 km2 (4,706 sq mi) (161st) |
Alábùgbé | |
• 2009 census | 243,304 |
• Ìdìmọ́ra | 19.7/km2 (51.0/sq mi) (188th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $1.141 billion |
• Per capita | $4,737 |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $635 million |
• Per capita | $2,635 |
HDI (2004) | ▲0.674 Error: Invalid HDI value · 120th |
Owóníná | Vanuatu vatu (VUV) |
Ibi àkókò | UTC+11 (UTC+11) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | ọ̀tún |
Àmì tẹlifóònù | 678 |
ISO 3166 code | VU |
Internet TLD | .vu |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Fanuatu, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.