Sẹ̀nẹ̀gàl (Faransé: le Sénégal) tabi Orile-ede Olominira ile Senegal je orile-ede ni Iwoorun Afrika.
Senegal ni Okun Atlantiki ni iwoorun, Mauritania ni ariwa, Mali ni ilaorun, ati Guinea ati Guinea-Bissau ni guusu. Sinu die lo ku ko yipo Gambia ka patapata si ariwa, ilaorun ati guusu, ibi to se ku nikan ni eti okun Atlanti Gambia Ifesi ile Senegal fe to 197,000 km², be si ni o ni onibugbe bi 13.7 legbegberun.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàl République du Sénégal | |
---|---|
Orin ìyìn: Pincez Tous vos Koras, Frappez les Balafons | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Dakar |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | French |
Lílò regional languages | Wolof, Soninke, Seereer-Siin, Fula, Maninka, Diola, |
Orúkọ aráàlú | Senegalese |
Ìjọba | Semi-presidential republic |
• President | Macky Sall |
• Prime Minister | Sidiki Kaba |
Independence | |
• from France | 4 April 1960 |
Ìtóbi | |
• Total | 196,723 km2 (75,955 sq mi) (87th) |
• Omi (%) | 2.1 |
Alábùgbé | |
• 2009 estimate | 12,534,000 (72nd) |
• Ìdìmọ́ra | 63.7/km2 (165.0/sq mi) (137th) |
GDP (PPP) | 2008 estimate |
• Total | $21.773 billion |
• Per capita | $1,739 |
GDP (nominal) | 2008 estimate |
• Total | $13.350 billion |
• Per capita | $1,066 |
Gini (1995) | 41.3 medium |
HDI (2007) | ▲0.464 Error: Invalid HDI value · 166th |
Owóníná | CFA franc (XOF) |
Ibi àkókò | UTC |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 221 |
Internet TLD | .sn |
Dakar ni oluilu re to wa lori Cap-Vert Peninsula ni eti Okun Atlantiki. Bi iye ida kan ninu meta awon ara Senegal ni won n gbe labe ila aini kakiriaye to je US$ 1.25 lojumo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Senegal, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.