Mali

Mali, fun tonibise bi Olominira ile Mali (Faransé: République du Mali), je orile-ede tileyika ni Apaiwoorun Afrika.

Mali ni bode mo Algeria ni ariwa, Nijer ni ilaorun, Burkina Faso ati Côte d'Ivoire ni guusu, Guinea ni guusu-iwoorun, ati Senegal ati Mauritania ni iwoorun. Itobi re fi die ju 1,240,000 km² lo pelu iye awon eniyan to ju egbegberun 14 lo. Oluilu re wa ni Bamako.

Olómìnira ilẹ̀ Málì
Republic of Mali

République du Mali
Motto: "Un peuple, un but, une foi"
"One people, one goal, one faith"
Orin ìyìn: Le Mali
"Mali"
Location of Málì
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Bamako
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaFrench
Vernacular languagesBambara
Orúkọ aráàlúMalian
ÌjọbaSemi-presidential republic
• Aare
Assimi Goïta
• Alakoso Agba
Choguel Kokalla Maïga
Ilominira 
latowo Fransi
• Kikede
September 22, 1960
Ìtóbi
• Total
1,240,192 km2 (478,841 sq mi) (24th)
• Omi (%)
1.6
Alábùgbé
• April 2009 census
14,517,176 (67th)
• Ìdìmọ́ra
11.7/km2 (30.3/sq mi) (215th)
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$15.084 billion
• Per capita
$1,129
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$8.774 billion
• Per capita
$656
Gini (1994)50.5
high
HDI (2007) 0.371
Error: Invalid HDI value · 178rd
OwónínáWest African CFA franc (XOF)
Ibi àkókòUTC+0 (GMT)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+0 (not observed)
Ojúọ̀nà ọkọ́otun
Àmì tẹlifóònù223
ISO 3166 codeML
Internet TLD.ml

Mali ni agbegbe mejo be sini awon bode re ni ariwa sun de arin Sahara, nigbati agbegbe apaguusu, nibi ti opolopo eniyan ngbe, ni awon odo Niger ati Sénégal. Ise agbe ati ise apeja ni won se ju nibe. Awon ohun alumoni Mali ni wura, uraniomu, ati iyo. Mali je ikan ninu awon orile-ede to je talaka julo mi agbaye.

Present-day Mali oni fi igba kan wa ni apa awon ile obaluaye meta ti Iwoorun Afrika to n dari idunadura kiri Sahara: Ile Obaluaye Ghana, ile Obaluaye Mali (nibiti orile-ede Mali ti gba oruko re), ati Ile Obaluaye Songhai. Ni opin awon odun 1800, Mali bo sowo awon ara Fransi, o di apa Sudan Fransi. Mali gba ilominira ni 1959 lapapo mo Senegal, gege bi Ile Apapo Mali. Leyin odun kan, Ile Apapo Mali di orile-ede alominira ile Mali. Leyin igba pipe ijoba egbe oloselu-kan, ifipagbajoba ni 1991 mu ilana-ibagbepo titun jade ati idasile Mali gege bi orile-ede toseluaralu egbe oloselu-pupo.



Itokasi

Tags:

AlgeriaBamakoBurkina FasoCôte d'IvoireGuineaMauritaniaNigerSenegalWest AfricaÈdè Faransé

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ÌránìTógòÈdè YorùbáMartin Luther King, Jr.Adolf SchärfÈdè TúrkìPalauÀtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè Olómìnira àgbáyéSteve GukasÌṣèlú ilẹ̀ GuineaÈdè FendaLíktẹ́nstáìnìAlejandro FallaÌtàn ìsèdálẹ̀ Ilé-Ifẹ̀Èdè IrelandOgun láàrin Ùgándà àti TànsáníàKárbọ̀nùLa MarseillaiseKlorínì5777 HanakiÈdè PólándìPópù VigiliusEuroWalther NernstGánàNarmerỌ̀rọ̀-ìṣeSan MàrínòChinaza UchenduManhattanLimaAjáJide KosokoMobi OparakuLyndon B. JohnsonMítàÁsíàAfrican-AmericanAdeniran OgunsanyaDẹ́nmárkìPatrick KoshoniÈdè ÍtálìWiki CommonsDagobert 3kẸ̀bùn Ọ́skàAndreas Seppi.uyMillicent Agboegbulem(6103) 1993 HVFilniusNevadaEhoroAlafẹfẹÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1896PerúẸkún ÌyàwóFally Ipupa.pwSunni🡆 More