Kenya

Kẹ́nyà tàbí Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyà je orile-ede ni Ìlaòrùn Áfríkà.

O dubule si eba Okun India, ni agedemeji aye, Kẹ́nyà ni bode mo Ethiópíà (ariwa), Sòmálíà (ariwailaorun), Tànsáníà (guusu), Ùgándà ati Lake Victoria (iwoorun), ati Orile ede Gúúsù Sudan (ariwaiwoorun). Oluilu re ni Nairobi. Awon onibugbe ibe ti po to 38 legbegberun.

Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyà
Republic of Kenya

Jamhuri ya Kenya (Swahili)
Motto: "Harambee" (Swahili)
"Let us all pull together"
Orin ìyìn: "Ee Mungu Nguvu Yetu"
(English: "O God of all creation")
Kenya
Kenya
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Nairobi
1°16′S 36°48′E / 1.267°S 36.800°E / -1.267; 36.800
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba
National languageSwahili
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2019)
  • 17.13% Kikuyu
  • 14.35% Luhya
  • 13.37% Kalenjin
  • 10.65% Luo
  • 9.81% Kamba
  • 5.85% Somalis
  • 5.68% Kisii
  • 5.23% Mijikenda
  • 4.15% Meru
  • 13.78% Other
Ẹ̀sìn
(2019)
Àdàkọ:Ublist
Orúkọ aráàlúKenyan
ÌjọbaUnitary presidential constitutional republic
• Ààrẹ
Uhuru Kenyatta
• Ìgbákejì Ààrẹ
William Ruto
• Speaker of the Senate
Kenneth Lusaka
• Speaker of the National Assembly
Justin Muturi
• Chief Justice
David Maraga
• Attorney General
Paul Kihara Kariuki
AṣòfinParliament
• Ilé Aṣòfin Àgbà
Senate
• Ilé Aṣòfin Kéreré
National Assembly
Independence
• from the United Kingdom
12 December 1963
• Republic declared
12 December 1964
Ìtóbi
• Total
580,367 km2 (224,081 sq mi) (48th)
• Omi (%)
2.3
Alábùgbé
• 2019 census
47,564,296 (29th)
• Ìdìmọ́ra
78/km2 (202.0/sq mi) (124th)
GDP (PPP)2020 estimate
• Total
$206.532 billion
• Per capita
$4,071
GDP (nominal)2020 estimate
• Total
$109.116 billion
• Per capita
$2,151
Gini (2014)42.5
medium · 48th
HDI (2018) 0.579
medium · 147th
OwónínáKenyan shilling (KSH)
Ibi àkókòUTC+3 (EAT)
Irú ọjọ́ọdúndd/mm/yy (AD)
Ojúọ̀nà ọkọ́left
Àmì tẹlifóònù+254
Internet TLD.ke
According to the CIA, estimates for this country explicitly take into account the effects of mortality because of AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex, than would otherwise be expected.

Awon Igberiko, ibile ati awon ipinsi

Kenya 
Provinces of Kẹ́nyà

Kenya pinsi awon igberiko 8 ti olori won n je Alakoso Igberiko (Aare lo n yan won). Awon igberiko wonyi (mkoa singular mikoa plural in Swahili) na tun je pinpin si awon ibile (wilaya). Awon ibile 69 lo wa. Awon ibile wonyi na tun je pipin si awon ipinsi 497 (taarafa). Awon ipinsi tu je pipin si 2,427 awon ibudo 2,427 (mtaa) ati omo ibudo 6,612 (mtaa mdogo).. Awon igberiko na niwonyi:

  1. Igberiko Aarin
  2. Igberiko Eti Okun
  3. Igberiko Apailaorun
  4. Igberiko Nairobi
  5. Igberiko Ariwa Apailaorun
  6. Igberiko Nyanza
  7. Igberiko Rift Valley
  8. Igberiko Apaiwoorun

Iye awon onibugbe awon ilu ninla

Ilu Iye eniyan
Nairobi 2 940 911
Mombasa 707 400
Nakuru 337 200
Kisumu 273 400
Eldoret 249 100
Nyeri 213 000
Machakos 179 500
Meru 140 900




Itokasi


Tags:

EthiópíàGúúsù SudanIndian OceanNairobiSòmálíàTànsáníàÌlaòrùn ÁfríkàÙgándà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

LimaISO 4217AyéÀsìá ilẹ̀ Bùrkínà FasòÀngólàAbubakar Olusola SarakiAmòfinPanamáLateef KayodeWikipẹ́díà l'édè YorùbáOrílẹ̀-èdè PalẹstínìKòmóròJessica TandyMons pubisÈdè Arméníà3460 AshkovaÌbálòpọ̀Lítíréṣọ̀Oṣù KẹrinSurinameLèsóthòISO 690Èdè JavaGánàIndependência totalSomaliaGreeksÍndíàÌránìMàláwìRoland BurrisWalther NernstSt. Louis474 PrudentiaJoe BidenXHTMLAlejandro FallaÈdè GermanyTháílàndìPatrick KoshoniOrílẹ̀ èdè AmericaSteve GukasVicente FernándezAlexander MackenzieSan Màrínò10 MarchSão Tomé and PríncipeÌjẹrò-ÈkìtìÀwọn èdè Índíà-EuropeÀjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-2020ÈrànkòrónàÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1896AlanineArméníàAbubakar Tafawa BalewaSlofákíàGùyánàOníṣègùnÈrànIlẹ̀ YorùbáNew York (Ìpínlẹ̀)Jẹ́mánìGbenga AlukoÈdè IrelandÈdè Slofákíà🡆 More