Majẹmu titun ni ìpín kejì tí Bíbélì mímọ Kristẹni.
Ó sọ nípa àwọn ẹ̀kọ́ àti ìgbẹ́ ayé Jesu,o tún sọ nípa ìgbé ayé àwọn Kristẹni.
Májẹ̀mú titun jẹ́ àpapọ̀ àwọn ìwé Kristẹni tí wón ko ní èdè Griki, oríṣi àwọn ènìyàn mimo ni ó ko àwọn ìwé yìí. Majẹmu titun ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjọ jẹ́ àpapọ̀ ìwé metadinlogbon.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Májẹ̀mú Titun, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.