Bọ́ọ̀lù-àfẹsègbá jẹ́ ọ̀kan lára àwọn eré-ìdárayá tó ní ṣe pèlú fífi ẹsẹ̀ gbá bọ́ọ̀lù.
Eré-ìdáraya h yìí pẹ̀ka sóríṣiríṣi ọ̀nà, ara rẹ̀ la ti rí association football, gridiron football tàbí American football tàbí Canadian football, Australian rules football, rugby union pẹ̀lú rugby league àti Gaelic football. Oríṣi ẹ̀ka bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá wọ̀nyí ní nǹkan tó pa wọ́n pọ̀, tí a mọ̀ sí kóòdù bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá
An attacking player (No. 10) attempts to kick the ball past the goalkeeper and between the goalposts to score a goal | |
Highest governing body | FIFA |
---|---|
Nickname(s) | Football, soccer, futbol, footy/footie, "the beautiful game" |
First played | Mid-19th century England |
Characteristics | |
Contact | Yes |
Team members | 11 per side |
Mixed gender | Yes, separate competitions |
Categorization | Team sport, ball sport |
Equipment | Football |
Venue | Football pitch |
Olympic | 1900 |
Oríṣiríṣi ìtọ́kasí ló wà fún bọ́ọ̀lù ìbílẹ̀ tí wọ́n ń gbá káàkiri àgbááyé. Ó sì ní òfin tó de wọ̀n, àwọn òfin yìí ti wà láti sẹ́ńtúrì kọkàndínlógún. Ìtànkálẹ̀ British Empire mú kí àwọn òfin yìí tàn káàkiri eré náà.
Ní ọdún 1888, wọ́n ṣe ìdásílẹ̀ The Football League ní England, èyí sì jẹ́ ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá alámọ̀dájú àkọ́kọ́. Ní sẹ́ńtúrì ogún, ọ̀pọ̀lọpọ̀ bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá lọ́ríṣiríṣi wá di ìlú-mọ̀ọ̀nká, tí wọ́n sì ń gbá káàkiri orílẹ̀-èdè ní àgbááyé.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Boolu-afesegba, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.