Jésù ará Násárẹ́tì (c.
5 BC/BCE – c. 30 AD/CE), tàbí Jésù Kírísítì tabi Jésù, jẹ́ ẹni tó ṣe kókó jùlọ, yàtọ̀ sí Ọlọ́run nínú Ẹ̀sìn Kírísítì, tí àwọn ẹlẹ́sìn náà gbà gẹ́gẹ́ bí Olùgbàlà Aráyé, èyí tí ó jẹ́ àsọtẹ́lẹ̀ ni Májẹ̀mú Láéláé nínú Bíbélì, tí gbogbo àwọn ẹlẹ́ṣin Kíristi tàbí irú wọn gbà pé òun ni Ọmọ Ọlọ́run àti àwòrán Ọlọ́run tí ó jí dìde nínú ipò òkú. Islamu gba Jesu gege bi woli ati Messiah. Ọ̀pọ̀ àwọn ẹ̀sìn mìíràn ni wọ́n tún tẹrí ba fún un lóríṣi ọ̀nà. Jésù jẹ́ ẹnìkan tó ṣe pàtàkì nínú ìtàn ọmọ ènìyàn.
Jésù ará Násárẹ́tì | |
---|---|
6th-century mosaic of Jesus at Basilica of Sant'Apollinare Nuovo in Ravenna. Though depictions of Jesus are culturally important, no undisputed record of what Jesus looked like is known to exist. | |
Ọjọ́ìbí | c. 4 BC/BCE Bethlehem, Judea, Ilẹ̀ọbalúayé Rómù (traditional); Nazareth, Galilee (historical Jesus) |
Aláìsí | c. 30 AD/CE Calvary, Judea, Ilẹ̀ọbalúayé Rómù (According to the New Testament, he rose on the third day after his death.) |
Cause of death | Crucifixion (Historically trusted, important meaning in Christian belief) No cause/death disputed (Islamic belief) |
Resting place | Traditionally and temporarily, a garden tomb located in what is now the Church of the Holy Sepulchre, Jerúsálẹ́mù. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Jésù, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.