Barack Obama: Olóṣèlú

Barack Hussein Obama Jr.

Ó jẹ́ òloṣèlú orílẹ̀ èdè Améríkà, ọmọ ilé ìgbìmó aṣòfin láti ìpínlè Illinois, ọmọ ẹgbé òṣèlú Democrat. Barack Obama jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn òṣèlú méjì tí wón figagbága láti jẹ Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Ẹni èkejì ni John Mccain. Ni ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 2008 Obama wọlé ìbò fún ipò Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Obama gorí oyè ní ogún jó osù kinni odún 2009. Barack Obama jé aláwọ̀ dúdú àkọ́kọ́ tí òkan nínú àwọn egbé òṣèlú nlá ti ilè Amẹ́ríkà fún ní ànfàní láti kópa nínú eré ìje àti di Ààrẹ ilè Amerika láti ẹgbẹ́ òṣèlú Democrat.

Barack Obama
Obama standing with his arms folded and smiling
44th President of the United States
In office
January 20, 2009 – January 20, 2017
Vice PresidentJoe Biden
AsíwájúGeorge W. Bush
Arọ́pòDonald Trump
United States Senator
from Illinois
In office
January 3, 2005 – November 16, 2008
AsíwájúPeter Fitzgerald
Arọ́pòRoland Burris
Member of the Illinois Senate
from the 13th district
In office
January 8, 1997 – November 4, 2004
AsíwájúAlice Palmer
Arọ́pòKwame Raoul
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Barack Hussein Obama II

Oṣù Kẹjọ 4, 1961 (1961-08-04) (ọmọ ọdún 62)
Honolulu, Hawaii, U.S.
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic
(Àwọn) olólùfẹ́
Àwọn ọmọ
  • Malia
  • Sasha
Àwọn òbí
  • Barack Obama Sr.
  • Ann Dunham
RelativesSee Family of Barack Obama
Education
AwardsNobel Peace Prize (2009)
Profile in Courage Award (2017)
SignatureBarack Obama: Ìgbésí ayé, Ìwé tó kọ, Àwọn ibùdó lori Interneti
Website

Ìgbésí ayé

Barack Obama: Ìgbésí ayé, Ìwé tó kọ, Àwọn ibùdó lori Interneti 
Barack àti ìyàwọ́ rẹ̀ Michelle Obama

Wón bí Barack Obama ní ìlú Honolulu, ìpínlè Hawaii ní ọdun 1961. Àwòn òbí ré rí ara won ní ìgbà tí wón nka ìwé ní ilé èkó Unifásítì Hawaii ní ìlu Manoa. Bàba rè wá láti orílè èdè Kenya. Barack Hussein Obama- àgbà, lọ ka ìwé nípa òrò ajé ní ilè Amerika. Ìya rè, ènìyàn funfun, ọmọ ilè Améríkà, Stanley Ann Dunham, jé ọmọ ilé èkó Unifásítì láti ìlu Wichitta, ìpínlè Kansas. Àwọn òbí ìya rè lòdì sí àjọṣe àwọn méjèjì, ṣùgbón wón fé ara wọn ní odún 1960. Ọdún méjì léhìn tí wón bí Obama, bàbá rè lọ si Howard fún ìtèsíwájú èkọ rè, ṣùgbón kò mú ẹbí rè lọ nítorí àìsí owó. Ní àìpé ọjó wón yapa. Ní ìgbà èkó rè ní Howard, Obama- àgbà fé Ruth Nidesand, ẹni tí ó bá padà sí orílè èdè Kenya léhìn ìparí èkò rè. Ruth Nidesand jé ìyàwó rè ẹ̀kẹ́ta, wón sì ní ọmọ méjì. Ní orílè èdè Kenya, Obama- àgbà bèrè iṣé ní ilé iṣé tí ó nwa epo ròbì, léhìn èyí, ó ṣiṣé fún ìjọba, gégébí olóòtú ètò ọrò ajé. Ó fi ojú kan ọmọ rè, Obama, ní ìgbàkan péré- ní ìgbà tí oní tòhún pé ọmọ ọdún méwàá. Obama- àgbà fi arapa nínú àgbákò ọkò nípa èyí tí ó sọ ẹsè méjèjì nù. Ní ìgbà tí ó pé ọmọ ọdún mérin-dí-láàdóta, ní ọdún 1982, ó sọ èmí rè nù nínú àgbákò ọkò.

Léhìn ìyapa pèlu bàba Obama, ìya rè fé Lolo Soetoro, ọmọ ilé èkó gíga unifasiti láti orílè èdè Indonesia. Ní ọdún 1967 ó sì bá Lolo Soetoro lọ sí Indonesia. Barack Obama ní ọbàkàn, obìnrin, ọmọ Lolo àti Stanley Ann. Stanley Ann Dunham pèhìndà ní ọdún 1995.

Ìwé tó kọ

  • Obama, Barack. Dreams from My Father: A Story of Race and Inheritance, Times Books, 1995. Reprint edition, 2004; ISBN 1-4000-8277-3
  • Obama, Barack. The Audacity of Hope: Thoughts on Reclaiming the American Dream, Crown, 2006. ISBN 0-307-23769-9.

Àwọn ibùdó lori Interneti

Àwọn ìtọ́kasí

Barack Obama: Ìgbésí ayé, Ìwé tó kọ, Àwọn ibùdó lori Interneti 
Wikinews ní ìròhìn lórí ọ̀rọ̀ yíì:
Wiki YorùbáBarack Obama: Ìgbésí ayé, Ìwé tó kọ, Àwọn ibùdó lori Interneti 
Wikiquote logo
Nínú Wikiquote a ó rí ọ̀rọ̀ tójẹmọ́:
Barack Obama: Ìgbésí ayé, Ìwé tó kọ, Àwọn ibùdó lori Interneti 
Wikisource has original text related to this article:

Tags:

Barack Obama Ìgbésí ayéBarack Obama Ìwé tó kọBarack Obama Àwọn ibùdó lori InternetiBarack Obama Àwọn ìtọ́kasíBarack Obama20 February2009IllinoisJohn MccainOlóṣèlúUSAÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

YemenJapanLítíọ̀mùÀkójọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ NàìjíríàSọrọ Nipa Awọn igiVanuatuLa MarseillaiseÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáGreeksÈdè SwatiAlejandro FallaÌwo Orí ilẹ̀ ÁfríkàSão Tomé and PríncipeÀwọn èdè oníjẹ́mánìIrinÌjẹrò-ÈkìtìViennaÈrànkòrónàMáltàMítàBíbélì Mímọ́Ida B. WellsSaint LuciaBàbà5 MayMain PageAurélio de Lira TavaresPétérù 1k ilẹ̀ Rọ́síàṢáínàBuenos AiresPuducherryEde Angas93 DaysWalther NernstLee Tockar(5163) 1983 TD2YorùbáSan MàrínòJacob ZumaNàìjíríàGoogleOrílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin ÁfríkàFilniusFiẹtnámDenmarkÒkun AtlántíkìPakistanYul EdochieÌdìbòyànÈdè ZuluTim Berners-LeeBaṣọ̀run GáàÀtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè Olómìnira àgbáyéAngolaGuinea TitunLíktẹ́nstáìnìÌbonItálíàAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ LereBurkina FasoÁntígúà àti BàrbúdàKurt Georg KiesingerYunifásítì PrincetonTẹknọ́lọ́jìISO 86019 AprilMarie-Joseph Motier, Marquis de LafayetteCristiano Ronaldo🡆 More