Ayé

Ayé, tàbí Ilé-ayé jẹ́ pálánẹ́ẹ̀tì kẹta ní ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ láti ọ̀dọ ọ̀run, ó sì jẹ́ èyí tí ó tóbi jùlo nínú àwọn pálánẹ́ẹ̀tì tí wọ́n ní ilẹ̀ tí ó ṣe é tẹ̀.

🜨

Ayé  🜨
Ayé
"The Blue Marble" photograph of Earth,
taken from Apollo 17
Ìfúnlọ́rúkọ
Ìpolongo Gbígbọ́i /ˈa/
Alápèjúwe earthly, tellurian, telluric, terran, terrestrial.
Àwọn ìhùwà ìgbàyípo
Àsìkò J2000.0
Aphelion152,098,232 km
1.01671388 AU
Perihelion 147,098,290 km
0.98329134 AU
Semi-major axis 149,598,261 km
1.00000261 AU
Eccentricity 0.01671123
Àsìkò ìgbàyípo 365.256363004 days
1.000017421 yr
Average orbital speed 29.78 km/s
107,200 km/h
Mean anomaly 357.51716°
Inclination 7.155° to Sun's equator
1.57869° to invariable plane
Longitude of ascending node 348.73936°
Argument of perihelion 114.20783°
Satellites 1 (the Òṣùpá)
Àwọn ìhùwà àdánidá
Iyeìdáméjì ìfẹ̀kiri 6,371.0 km
Ìfẹ̀kiri alágedeméjì 6,378.1 km
Ìfẹ̀kiri olóòpó 6,356.8 km
Flattening 0.0033528
Circumference 40,075.16 km (equatorial)
40,008.00 km (meridional)
Ààlà ojúde 510,072,000 km2

148,940,000 km2 land (29.2 %)

361,132,000 km2 water (70.8 %)
Ìpọ̀sí 1.08321 × 1012 km3
Àkójọ 5.9736 × 1024 kg
Iyeìdáméjì ìṣùpọ̀ 5.515 g/cm3
Equatorial surface gravity9.780327 m/s2
0.99732 g
Escape velocity11.186 km/s
Sidereal rotation
period
0.99726968 d
23h 56m 4.100s
Equatorial rotation velocity 1,674.4 km/h (465.1 m/s)
Axial tilt 23°26'21".4119
Albedo0.367 (geometric)
0.306 (Bond)
Ìgbónásí ojúde
   Kelvin
   Celsius
minmeanmax
184 K287.2 K331 K
-89.2 °C14 °C57.8 °C
Afẹ́fẹ́àyíká
Ìfúnpá ojúde 101.325 kPa (MSL)
Ìkósínú 78.08% nitrogen (N2)
20.95% oxygen (O2)
0.93% argon
0.038% carbon dioxide
About 1% water vapor (varies with climate)

Ilé-ayé jé pálánẹ́ẹ̀tì àkọ́kọ́ tí ó ní omi tó ń sàn ní òde ojú rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ sìni Ilé-ayé nìkan ni pálánẹ́ẹ̀tì tí a mọ̀ ní àgbáńlá ayé. Ojú-òrun (atmosphere) jẹ́ kìkì nitrogen àti oxygen tí ó ń dà àbò bo ilé-ayé lọ́wọ́ àtaǹgbóná (radiation) tó léwu sí ènìyàn. Bákan náà ojú-òrun kò gba àwọn yanrìn-òrun láàyè láti jábọ́ sí ilé-ayé nípa sísun wọ́n níná kí wọ́n ó tó lè jábọ́ sí ilé-ayé.

Ayé
Òṣùpá ati Ilé-ayé

Àwọn Ìtókasí


Tags:

Pálánẹ́tìSun🜨

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

30 Oṣù KẹtaSunny OfeheDeborah AbiodunBurkina FasoWikiVladimir LeninSudanFrancisco Diez CansecoBristolOṣù Kínní 135 December29 Oṣù KẹtaAmmanIfáPete ConradKroatíàOdunlade AdekolaNọ́rwèyÌtàn àkọọ́lẹ̀ YorùbáHenri PoincaréÈdè TàmilUju UgokaChinese languageÈdè RomaníàC++Gúúsù Amẹ́ríkàOrílẹ̀ èdè AmericaYewande SadikuBobriskyJẹ́mánìBeirut5 Oṣù KẹtaÀsà ilà kíkọ ní ilé Yorùbá14 Oṣù KẹtaWeimar OlómìniraÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáKarachiGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè13 DecemberṢàngóFránsìÀtòjọ àwọn olórin ilẹ̀ NàìjíríàCharles MansonOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàBucharestỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Ìpínlẹ̀ DeltaYukréìnBaháíANgozi Okonjo-IwealaÈdè PólándìKọ̀nkọ̀2537 GilmoreÈdè ÍgbòOṣù Kínní 12SociologyMàláwìOrúkọ YorùbáẸ̀yà ara ìfọ̀D. O. FagunwaUSAAyo AdesanyaMicrosoftDavid ToroEwì27 Oṣù KẹtaMọ́remí Ájàṣoro5 NovemberÌbálòpọ̀9 December🡆 More