Ìpògùn tí ṣe ẹ̀ka sáyẹ́nsì oníṣeẹ̀dá, jẹ́ ẹ̀kọ́ìwádìí ìkósínú, ìní àti ìwùwà ohun èlò.
Kẹ́místrì únsọ nípa àwọn átọ́mù àti ìbáraṣepọ̀ wọn pẹ̀lú àwọn átómù míràn, àgàgà pẹ̀lú àwọn ìní àwọn ìsopọ̀ kẹ́míkà. Kẹ́místrì tún úndálórí àwọn ìbáraṣepọ̀ láàrin àwọn átọ́mù (tàbí ọ̀pọ̀ àwọn átọ́mù) àti orísirísi irú okun (f.a. àwọn ìdaramọ́ra f fọ́tòkẹ́míkà, àwọn ìyípadà nínú ojúwà èlò, ìyàsọ́tọ̀ àwọn àdàlú, àwọn ìní pólímẹ̀r, at.b.b,lọ).
Kẹ́místrì únjẹ́ pípè nígbà míràn bíi "sáyẹ́nsì agbàrin" nítorípé ó so ìṣeẹ̀dá mọ́ àwọn sáyẹ́nsì onítaládánidá míràn bíi Jẹ́ọ́lọ́jì àti baolọ́jì. Kẹ́místrì jẹ́ ẹ̀ka sáyẹ́nsì oníṣeẹ̀dá sùgbọ́n ó yàtọ̀ sí físíksì.
Àwọn ìtúnṣe àpòpọ̀ògùn ní àwọn òfin dájú tó ṣàkóso wọn, tí wọ́n ti dí òye àpilẹ̀sẹ̀ nínú ìpògùn. Díẹ̀ nínú wọn nìyí:
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àdàkọ:Ìbọ̀sẹ̀ sáyẹ́nṣì onítaládánidá
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Kẹ́místrì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.