Mẹ́ksíkò

Àwọn Ìpínlẹ̀ Mẹ́síkò Aṣọ̀kan (Estados Unidos Mexicanos lédè Sípéènì) ,tàbí Mẹ́síkò ní ṣókí, jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Apá Àríwá Amẹ́ríkà.

Èdè Sípéènì ni wọ́n ń sọ níbẹ̀. Apá gúúsù orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ló wà. Àwọn ọmọ Sípéènì ṣẹ́gun Mẹ́síkò lọ́dún 1519. Ọ̀pọ̀ àwọn Mestizo wà nínú àwọn ènìyàn tó wà ní Mẹ́síkò, ìyẹn ni àwọn tí òbí wọn jẹ́ apá kan Òyìnbó àti apá kan ọmọ ìbílẹ̀ Mẹ́síkò. Lọ́dún 1821 orílẹ̀-èdè yìí gbà òmìnira lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjà àti ogun. Wọ́n di Orílẹ̀-Èdè Olómìnira lọ́dún 1824.

Àwọn Ìpínlẹ̀ Mẹ́síkò Aṣọ̀kan
United Mexican States

Mexihco Tlacetililli Tlahtohcayotl;
Flag of Mẹ́síkò
Àsìá
Coat of arms ilẹ̀ Mẹ́síkò
Coat of arms
Orin ìyìn: "Himno Nacional Mexicano"
Mexican National Anthem
National seal:
Seal of the United Mexican States Mẹ́ksíkò
Location of Mẹ́síkò
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Mexico City
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaNone at federal level.
Spanish (de facto)
National languageÈdè Sípéènì, àti Èdè Ìbílẹ̀ Mẹ́síkò 62
Orúkọ aráàlúMexican
ÌjọbaFederal presidential republic
• President
Andrés Manuel López Obrador
AṣòfinCongress
• Ilé Aṣòfin Àgbà
Senate
• Ilé Aṣòfin Kéreré
Chamber of Deputies
Independence 
from Spain
• Declared
September 15, 1810
• Recognized
September 27, 1821
Ìtóbi
• Total
1,972,550 km2 (761,610 sq mi) (15th)
• Omi (%)
2.5
Alábùgbé
• mid-2008 estimate
111,211,789 (July - 2009) (11th)
• 2005 census
103,263,388
• Ìdìmọ́ra
55/km2 (142.4/sq mi) (142nd)
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$1,559 billion (11)
• Per capita
$14,560
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$ 1,143 billion (13)
• Per capita
$10,235
Gini (2008) 46.1
Error: Invalid Gini value
HDI (2008) 0.842
Error: Invalid HDI value · 51st
OwónínáPeso (MXN)
Ibi àkókòUTC-8 to -6 (Official Mexican Timezones)
• Ìgbà oru (DST)
UTC-7 to -5 (varies)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù52
Internet TLD.mx



Itokasi

Tags:

Àríwá Amẹ́ríkà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ISO 233GánàNọ́rwèyISO/IEC 8859-8OyunISO 3166-2VGeorgios KafantarisKathy Bates.ecGÀjọ Ìlera ÀgbáyéHypertext Transfer ProtocolÀsìá ilẹ̀ Bósníà àti HẹrzẹgòfínàBostonArizonaDeutschlandliedFederalismKarachi110 filmÀyànÀjọ MAMSERAkanlo-edeOwóWikiWiki CommonsMicrolophusTripolitáníàPierre NkurunzizaAalo oòrùn àti osupaA. Philip RandolphISO/IEC 14443Àdìtú Olódùmarè.amBordeaux.vgTaj MahalASEANIndia ArieISO 15897Dẹ́nmárkìCherFJoel McHaleISO 14000Babatunde OmidinaISO/IEC 7813Bahia.nl.rsÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020ISO/IEC 17024ISO 14644-4Òrò àyálò Yorùbá.rwAlice BradyUnited Nations Development ProgrammePaul BiyaÈdè LárúbáwáKontagoraJazzKòlómbìàAaliyah.yu.ptISO 2788Kofi Annan🡆 More