90°26′06″E / 27.417°N 90.435°E / 27.417; 90.435 Ileoba ile Bhutan (pípè /buːˈtɑːn/) je orile-ede tileyika ni Guusu Asia, to budo si apailaorun eti awon Oke Himalaya o si ni bode ni guusu, ilaorun ati iwoorun pelu orile-ede Olominira ile India ati ni ariwa pelu Tibet.
Awon ara Bhutan n pe orile-ede won ni Druk Yul (Dzongkha: [འབྲུག་ཡུལ་ 'drug yul] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) to tumo si "Ile Dragon" ni ede Tibet. Awon ara Bhutan je eya eniyan Tibet. Bakanna wo tun ni esin ati asa pelu awon ara Tibet.
Ilẹ̀ọba ilẹ̀ Bhùtán Kingdom of Bhutan འབྲུག་ཡུལ་ Brug rGyal-Khab (Wylie) Dru Gäkhap | |
---|---|
Orin ìyìn: Druk Tsendhen | |
Olùìlú | Thimphu |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Dzongkha |
Orúkọ aráàlú | Bhutanese |
Ìjọba | Constitutional democratic monarchy |
• King | Jigme Khesar Namgyel Wangchuck (འཇིགས་མེད་གེ་སར་རྣམ་རྒྱལ་དབང་ཕྱུག་) |
• Prime Minister | Tshering Tobgay (ཚེ་རིང་སྟོབས་རྒྱས།) |
Formation Early 17th century | |
• Wangchuk Dynasty | 17 December 1907 |
• Constitutional Monarchy | 2007 |
Ìtóbi | |
• Total | 38,394 km2 (14,824 sq mi) |
• Omi (%) | <1 (estimate) |
Alábùgbé | |
• July 2009 estimate | 691,141 (163rd) |
• 2005 census | 634,982 |
• Ìdìmọ́ra | 18.1/km2 (46.9/sq mi) (154th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $3.518 billion |
• Per capita | $5,212 |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $1.269 billion |
• Per capita | $1,880 |
HDI (2007) | ▲ 0.619 Error: Invalid HDI value · 132nd |
Owóníná | Ngultrum2 (BTN) |
Ibi àkókò | UTC+6:00 (BTT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+6:00 (not observed) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left |
Àmì tẹlifóònù | 975 |
ISO 3166 code | BT |
Internet TLD | .bt |
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Bhùtán, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.