Alibéníà

Alibéníà (i /ælˈbeɪniə/ al-BAY-nee-ə, Àdàkọ:Lang-sq, Gheg Albanian: Shqipnia/Shqypnia), lonibise bi Orileominira ilẹ̀ Alibéníà (Àdàkọ:Lang-sq, pipe Àdàkọ:IPA-sq; Gheg Albanian: Republika e Shqipnísë), je orile-ede ni Guusuilaorun Europe, ni agbegbe awon Balkani.

O ni bode mo Montenegro ni ariwailaorun, Kosovo[a] ni riwailaorun, Orileominira ile Makedonia ni ilaorun ati Girisi ni gusu ati gusuilaorun. O ni eti-omi ni egbe Omi-okun Adriatiki ni iwoorun, ati legbe Omi-okun Ionia ni gusiiworun. O fi iye to din ni 72 km (45 mi) jinna si Italy, nikoja Strait of Otranto to ja Adriatic Sea po mo Ionian Sea. Albáníà je omo egbe UN, NATO, Agbajo fun Abo ati Ifowosowopo ni Europe, Igbimo ile Europe, Agbajo Owo Agbaye, Agbajo Ipade Onimale be sini omo egbe lati ibere Isokan fun Mediteraneani. Albania ti fe di omo egbe Isokan Europe lati January 2003, be sini o ti toro lati di omo egbe lati 28 April 2009.

Orílẹ̀òmìnira ilẹ̀ Albáníà
Republic of Albania

Republika e Shqipërisë
Orin ìyìn: [Himni i Flamurit] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  
Hymn to the Flag
Ibùdó ilẹ̀  Alibéníà  (green) on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Alibéníà  (green)

on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Tirana
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaAlbanian1
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
92% Albanians,
6% Greeks, 2% others
Orúkọ aráàlúAlbanian
ÌjọbaOrílẹ̀òmìnira oníléaṣòfin
• Ààrẹ
Ilir Meta
• Alákóso Àgbà
Edi Rama
Formation
• Principality of Arbër
1190
• League of Lezhë
2 March 1444
• Independence from the Ottoman Empire
28 November 1912
• Recognized by the Great Powers
2 December 1912
• Current Constitution
28 November 1998
Ìtóbi
• Total
28,748 km2 (11,100 sq mi) (143rd)
• Omi (%)
4.7
Alábùgbé
• 2010 estimate
3,195,000 (136th)
• 2001 census
3,069,275
• Ìdìmọ́ra
111.1/km2 (287.7/sq mi) (63)
GDP (PPP)2010 estimate
• Total
$23.864 billion
• Per capita
$7,453
GDP (nominal)2010 estimate
• Total
$11.773 billion
• Per capita
$3,677
Gini (2005)26.7
Error: Invalid Gini value
HDI (2010) 0.719
Error: Invalid HDI value · 64th
OwónínáLek (ALL)
Ibi àkókòUTC+1 (CET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+2 (CEST)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù355
ISO 3166 codeAL
Internet TLD.al
  1. Greek, Macedonian and other regional languages are government-recognized minority languages.

Albáníà je oseluarailu onileasofin pelu itokowo toun yipada. Oluilu Albáníà, Tirana, je ile fun awon eniyan bi 600,000 ninu awon eniyan 3,000,000 to wa lorile-ede na. Atunse oja alominira ti si orile-ede sile fun inawo idagbasoke latokere, agaga fun idagbasoke okun ati eto irinna.



Itokasi

Tags:

Council of EuropeEuropean UnionFáìlì:En-us-Albania.oggGbígbọ́GreeceItalyKosovoMontenegroNATORepublic of Macedoniaen:Wikipedia:IPA for Englishen:Wikipedia:Pronunciation respelling key

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ANSI escape codeMáàdámidófòKonrad LorenzFISO/IEC 8859-3Paul BiyaKọ́ngrẹ́ẹ̀sì Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàISO 31000ISO 3103Pọ́rtúgàl.soISO 9ISO 26000Ionuț Silaghi de OasSheraton Lagos HotelISO 14644-9ÌjọbaISO 103032019 wiwo ile-iwe ni EkoISO 3166-3PólándìISO 13567Banke Meshida LawalWAmòfinAlbert LutuliÈlòÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáIlẹ̀ YorùbáISO 15022Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìAkademio de EsperantoISO 9241ÍndíàArméníà.gb(9981) 1995 BS3OSI modelÌjẹ̀bú-ÒdeNew York.bgGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèFulgencio Batista.niAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ewekoro.yeÒjò.gwMaya AngelouCharles Glover BarklaISO 8601Tony ElumeluISO/IEC 27002ISO 1000.liISO/IEC 27003JPEG 2000Ẹranko elégungunEre idarayaTáyọ̀ AwótúsìnISO 15189CasablancaÀrúbà🡆 More