Látfíà (Àdàkọ:Lang-lv), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Látfíà (Àdàkọ:Lang-lv) je orile-ede ni agbegbe Baltiki ni Apaariwa Europe.
O ni bode ni ariwa mo Estonia (343 km), ni guusu mo Lithuania (588 km), ni ilaorun mo Rosia (276 km), ati ni guusuilaorun mo Belarus (141 km). Niwaju Omi-okun Baltiki ni iwoorun ni Swidin wa. Agbegbe Látfíà borile to to 64,589 km2 (24,938 sq mi) o si ni ojuoju tutu kakiri odun.
Republic of Latvia Latvijas Republika | |
---|---|
Ibùdó ilẹ̀ Látfíà (dark green) – on the European continent (light green & dark grey) | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Riga |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Latvian |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 62.1% Latvians 26.9% Russians 3.3% Belarusians 2.2% Ukrainians 5.5% others |
Orúkọ aráàlú | Latvian |
Ìjọba | Parliamentary republic |
• President | Egils Levits |
• Prime Minister | Arturs Krišjānis Kariņš |
• Speaker of the Saeima | Ināra Mūrniece |
Independence from German Empire and Russia | |
• Declared1 | November 18, 1918 |
• Recognized | January 26, 1921 |
• Soviet occupation | August 5, 1940 |
• Nazi German occupation | July 10, 1941 |
• Soviet occupation | 1944 |
• Announced | May 4, 1990 |
• Restored | September 6, 1991 |
Ìtóbi | |
• Total | 64,589 km2 (24,938 sq mi) (124th) |
• Omi (%) | 1.57% (1,014 km2) |
Alábùgbé | |
• 2016 estimate | ▼ 1,953,200 (148rd) |
• 2011 ppl census | 2,067,887 |
• Ìdìmọ́ra | 34.3/km2 (88.8/sq mi) (166th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $32.234 billion |
• Per capita | $14,254 |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $26.247 billion |
• Per capita | $11,607 |
Gini (2003) | 37.7 medium |
HDI (2008) | ▲ 0.866 Error: Invalid HDI value · 48th |
Owóníná | Euro (EUR) |
Ibi àkókò | UTC+2 (EET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+3 (EEST) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | +371 |
ISO 3166 code | LV |
Internet TLD | .lv |
1 Latvia is de jure continuous with its declaration November 18, 1918. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Látfíà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.