John Maynard Keynes, 1st Baron Keynes ( /ˈkeɪnz/ KAYN-z; 5 June 1883 – 21 April 1946), CB, je ara Britani aseoro-okowo ti eroinu re ko ipa pataki lori irojinle ati imuse oro-okowotitobi odeoni, ati awon iselu oro-okowo awon ijoba.
O se atunse gidigidi ise tele lori awon ohun toun fa iyipo osowo, o si polongo fun ilo awon eto isenawo ati oro owo lati satunse ipa buburu awon economic ifaseyin oro-okowo ati itelole oro-okowo. Awon eroinu re ni won di pepe fun ile-eko ero toun je oro-okowo Keynes, ati iru awon to wa lati inu re.
Keynesian economics | |
---|---|
Born | Cambridge, England | 5 Oṣù Kẹfà 1883
Died | 21 April 1946 Firle, East Sussex, England | (ọmọ ọdún 62)
Nationality | British |
Field | Political economy, probability |
Alma mater | King's College, Cambridge |
Opposed | Marx · Hayek · Walras · Marshall · Pigou |
Influences | Smith · Ricardo · Hume · Mill · Malthus · Gesell · Moore · Marshall · Wicksell · Robertson |
Influenced | Whitaker · Lynch · Kalecki · Kuznets · Samuelson · Hicks · Shackle · Vickrey · Galbraith · Minsky · Shiller · Stiglitz · Krugman · Roubini |
Contributions | Macroeconomics, Keynesian Economics, Liquidity preference, Spending multiplier, Aggregate Demand-Aggregate Supply model |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article John Maynard Keynes, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.