Màláwì

Màláwì ( /məˈlɑːwi/; Chichewa Àdàkọ:IPA-ny), lonibise bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Màláwì, je orílẹ̀-èdè àdèmọ́àrinlẹ̀ kan ni guusuilaorun Afrika to je mi mo tele bi Ilẹ̀ Nyasa.

O ni bode mo Zambia ni ariwaiwoorun, Tanzania ni ariwailaorun, ati Mozambique ni ilaorun, guusu ati iwoorun. Orile-ede na je pinpinniya si Tanzania ati Mozambique pelu Omi-adagun Malawi. Malawi tobi to 118,000 km2 (45,560 sq mi) pelu awon alabugbe ti idiye won ju 13,900,000 lo. Oluilu re ni Lilongwe, to tun je ilu totobijulo ni be; ikeji totobijulo ni Blantyre ati iketa ni Mzuzu. Malawi bi oruko re wa lati Maravi, oruko atijo fun awon Nyanja ti won budo si be. Won tun unpe orile-ede yi bi "Ọkàn Alọ́wọ́rọ́ Afrika".

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Màláwì
Republic of Malawi

[Chalo cha Malawi, Dziko la Malaŵi] error: {{lang}}: text has italic markup (help)
Motto: Unity and Freedom
Òkan àti Òmìnira
Orin ìyìn: [Mulungu dalitsa Malaŵi] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  (Chichewa)
"Oh God Bless Our Land of Malawi"
Màláwì
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Lilongwe
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaEnglish
Chichewa
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2008)
Chewa 32.6%
Lomwe 17.6%
Yao 13.5%
Ngoni 11.5%
Tumbuka 8.8%
Nyanja 5.8%
Sena 3.6%
Tonga 2.1%
Ngonde 1%
other 3.5%
Orúkọ aráàlúMalawian
ÌjọbaOrílẹ̀-èdè olómìnira oníàrẹ onísọ̀kan
• Ààrẹ
Lazarus Chakwera
• Igbákejì Ààrẹ
Saulos Chilima
AṣòfinIlé Ìgbìmọ̀ Aṣofin
Ìlómìnira
• látọwọ́ Brítánì
July 6, 1964
Ìtóbi
• Total
118,484 km2 (45,747 sq mi) (99th)
• Omi (%)
20.6%
Alábùgbé
• 2010 estimate
14,901,000 (64th)
• 1998 census
9,933,868
• Ìdìmọ́ra
128.8/km2 (333.6/sq mi) (86th)
GDP (PPP)2011 estimate
• Total
$13.901 billion
• Per capita
$860
GDP (nominal)2011 estimate
• Total
$5.673 billion
• Per capita
$351
Gini (2008)38
medium
HDI (2008) 0.493
Error: Invalid HDI value · 160th
OwónínáKwacha (D) (MWK (£1.00= 265 kwachas))
Ibi àkókòUTC+2 (CAT)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+2 (not observed)
Ojúọ̀nà ọkọ́òsì
Àmì tẹlifóònù+265
ISO 3166 codeMW
Internet TLD.mw
1 Population estimates for this country explicitly take into account the effects of excess mortality due to AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex than would otherwise be expected.
2Information is drawn from the CIA Factbook unless otherwise noted.





Itokasi

Tags:

AfrikaLilongweMozambiqueTanzaniaZambiaen:Wikipedia:IPA for English

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

John LewisÀgùàlàÀwùjọ tonísáyẹ́nsìOjúewé Àkọ́kọ́UNESCOỌ̀rọ̀ ìṣeBlaise PascalAyéBobriskyÒdòdóJoe BidenÀwọn ará Jẹ́mánìAdvanced Audio CodingẸyẹ18 NovemberÒkun MẹditéránìÀríwá Amẹ́ríkàGoogleAgbègbè àkókòFacebookItan Ijapa ati Aja7 AugustIṣẹ́ ọnàOrílẹ̀ èdè AmericaRómùAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéÌwéPaul OmuGhánàKirgistaniSaint Kitts àti NevisFránsìAdeola OlubamijiOṣù KẹtaỌ̀rúnmìlà2023AustrálíàIlẹ̀ọbalúayé AustríàX8 AprilCAmẹ́ríkàn futbọ́ọ̀lùZincKàlẹ́ndà GregoryOnome ebiKarachiLuxembourgÍsráẹ́lìÈdè Gẹ̀ẹ́sìRigaFunke AkindeleOrúkọ ìdíléNikarágúàDNA1 NovemberOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìOdunlade AdekolaṢàngóFestus KeyamoNapoleon 3kÀrún èrànkòrónà ọdún 2019AllahChristian BaleMartin Luther🡆 More