Roger Federer

Roger Federer (Pípè nì Jẹ́mánì: ) (ojoibi 8 August 1981) je agba tenis ara Switsalandi to di Ipo No.

1 ATP mu fun rekodu ose 237 nitelentele lati 2 February 2004 de 18 August 2008. Federer ti di ipo kinni mu fun apapo ose 285, to fi ose kan din si rekodu ose 286 ti Pete Sampras ni. Titi di 28 May 2012, ohun lo wa ni Ipo No. 3 Lagbaye. Federer ti gba ife-eye Grand Slam enikan awon okunrin ni igba 16 to je rekodu. O je ikan ninu awon okunrin atayo to gba gbogbo Grand Slam ati ikan ninu awon eniyan meta (pelu Andre Agassi ati Rafael Nadal) to seyi lori papa itayo otooto meta (papa alamo, onikoriko, ati olojulile). Ohun nikan ni okunrin atayo ninu tenis titi doni to de idopin idije Grand Slam kookan ni emarun o kerejulo ati idopin ikookan awon Idije ATP Masters 1000 mesesan. Opo awon olutuwo ere-idaraya, olugbewo tenis, ati awon atayo lowo ati tele gba pe Federer ni atayo tenis to gbokikijulo.

Roger Federer
Roger Federer
Federer at the 2009 Wimbledon Championships
Orílẹ̀-èdèRoger Federer Switzerland
IbùgbéWollerau, Switzerland and Dubai, United Arab Emirates
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kẹjọ 1981 (1981-08-08) (ọmọ ọdún 42)
Basel, Switzerland
Ìga1.85 m (6 ft 1 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1998
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (one-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó$76,541,427
  •  1st all-time leader in earnings
Ẹnìkan
Iye ìdíje885–200 (81.57% in ATP World Tour and Grand Slam main draw matches, and in Davis Cup)
Iye ife-ẹ̀yẹ77 (4th in the Open Era)
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (2 February 2004)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 7 (11 November 2013)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (2004, 2006, 2007, 2010)
Open FránsìW (2009)
WimbledonW (2003, 2004, 2005, 2006, 2007, 2009, 2012)
Open Amẹ́ríkàW (2004, 2005, 2006, 2007, 2008)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje ATPW (2003, 2004, 2006, 2007, 2010, 2011)
Ìdíje ÒlímpíkìRoger Federer Silver medal (2012)
Ẹniméjì
Iye ìdíje120–80 (60% in ATP World Tour and Grand Slam main draw matches, and in Davis Cup)
Iye ife-ẹ̀yẹ8
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 24 (9 June 2003)
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà3R (2003)
Open Fránsì1R (2000)
WimbledonQF (2000)
Open Amẹ́ríkà3R (2002)
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn
Ìdíje ÒlímpíkìRoger Federer Gold medal (Àdàkọ:OlympicEvent)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Hopman CupW (2001)
Last updated on: 24 January 2013.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Adíje fún Switzerland Switzerland
Men's Tennis
Wúrà 2008 Beijing Doubles
Fàdákà 2012 London Singles



Itokasi


Tags:

Andre AgassiList of ATP number 1 ranked singles playersPete SamprasRafael Nadalen:WP:IPA for German

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ẹ̀tọ́-àwòkọIni Dima-OkojieMegawati SukarnoputriÒfinỌ̀rànmíyànSean ConneryDomain Name SystemAustríàFáwẹ̀lì YorùbáKarachiAustrálíà2024Àwọn orin ilẹ̀ YorùbáLinuxDapo AbiodunBarbara SokyIsiaka Adetunji AdelekeÁsíàÈdèẸ̀lẹ́ktrọ́nùOṣù Kínní 7Àwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Olu FalaeEwìPópù Pius 11kÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáRọ́síàR. KellyWalter MatthauVladimir NabokovLyndon B. Johnson30 MarchGlobal Positioning SystemLebanonÌtànÌsirò StatistikiMẹ́ksíkòẸ̀bùn Nobel nínú Lítíréṣọ̀YMathimátíkìÈdè FínlándìOranmiyanOperating SystemÈdè Rọ́síàEthiopiaÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Ludwig van BeethovenGuinea-BissauKetia MbeluÀríwá Amẹ́ríkàMao ZedongIgbeyawo IpaWikipedia🡆 More