Open Austrálíà

Open Australia je ikan ninu awon idije Grand Slam merin to uwaye ninu ere-idaraya alagbase Tenis.

O unwaye lodoodun ni Australia labe ase Tennis Australia, teletele tounje Egbe Ajose Tenis Australia (Lawn Tennis Association of Australia, LTAA) beesini idije akoko re waye lori papa isere kriket ni Melbourne ni 1905. Loni won unpe ibe ni Albert Reserve Tennis Centre.

Open Austrálíà
Australian Open
Official website
IbùdóMelbourne
Open Austrálíà Australia
PápáMelbourne Park
Orí pápáPlexicushion Prestige
Men's draw128S / 128Q / 64D
Women's draw128S / 96Q / 64D
Ẹ̀bùn owóA$23,140,000 (2009)
Grand Slam
Open Austrálíà
Rod Laver Arena je ikan ninu awon papa ibi ti Open Australia ti unwaye.

Itan

Open Australia koko bere bi Idije-eye Australasia (Australasian Championships) ko to wa di Idije-eye Australia (Australian Championships), ni 1927 to si di Open Australia (Australian Open) ni 1969.. Open Australia di sisi sile, eyun open, fun awon osise agba tenis ni odun 1969, odun kan leyin ti awon idije Grand Slam meta yioku ti di open fun awon osise agba tenis.




Itokasi

Tags:

AustraliaMelbourneTennis

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

C Sharp (programming language)Computer Graphics MetafileISO/IEC 27004Kàsínò.jeAdeniran Ogunsanya College of Education.yeCelestial Church of ChristÀrúbàJBIGISO 31-5Àdéhùn VersaillesPatty ObasiKúbàYoichiro NambuPragueISO/IEC 8859-10ISO 2788Ọjọ́SVOPCISO/IEC 64628 AprilFirginiaISO 15189Àwọn Òpó Márùún ÌmàleÀwọn Amino acidISO 5964Àdírẹ́ẹ̀sì IPAlice BradyWashington, D.C.ISO 14750.scÌwé EksoduTony ElumeluTaj MahalBiodun JeyifoISO/IEC 8859-2BáháráìnìISO 9126KlorínìInternational Organization for StandardizationÈdè YorùbáISO 20022FederalismISO 6344ISO 9241ISO/IEC 8859ISO/IEC 80000ẸrankoISO 9660Òrò àyálò YorùbáAlbert EinsteinÍndíàClaire TrevorDaniel KahnemanTwitterISO/IEC 27000-seriesRita HayworthWolé Olánipẹ̀kun.ytUnited Nations Development ProgrammeISO 5775ÀrokòPDF/ALitasOffice Open XML.ttMultibus🡆 More