Instagram

Instagram tí wọ́n tún máa ń pè ní kúkúrú ní IG tàbí Insta) jẹ́ ìkànnì ayélujára abánidọ́rẹ̀ẹ́ aláwòrán àti fídíò tí ilé iṣẹ́ Facebook ní tí ó gúnwà sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà .

Ọ̀gbẹ́ni Kevin Systrom àti Mike Krieger ní wọ́n ṣẹ̀dá rẹ̀ lọ́dún 2010 kí ilé iṣẹ́ Facebook tó wà rà á lọ́wọ́ wọn. Orí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká tí ó ní èròjà ayélujára Áńdọ́rọ́ídì ní wọ́n tí máa ń lo Instagram. Àwòrán àti fídíò ni àwọn ènìyàn máa ń ṣáfihàn àti dọ́rẹ̀ẹ́ lé ní ìkànnì Instagram. Instagram jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú àwọn ìkànnì ayélujára abánidọ́rẹ̀ẹ́ tí ó gbajúmọ̀ jùlọ. Àwọn ènìyàn jàǹkọ̀jàǹkọ̀, pàápàá jùlọ àwọn eléré ìdárayá, agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá, àwọn olórin ni wọ́n atẹ̀lé jùlọ lórí Instagram. Cristiano Ronaldo, gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́kà agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ló ní atẹ̀lé jù ní Instagram.

Instagram
Instagram
Instagram
Original author(s)Kevin Systrom, Mike Krieger
Developer(s)Facebook, Inc.
Initial releaseOṣù Kẹ̀wá 6, 2010; ọdún 13 sẹ́yìn (2010-10-06)
Operating systemiOS, Android, Windows
Size123.8 MB (iOS)
40.76 MB (Android)
Available inEnglish, Croatian, Czech, Danish, Dutch, Finnish, French, German, Greek, Hindi, Hungarian, Indonesian, Italian, Japanese, Korean, Malay, Norwegian Bokmål, Polish, Portuguese, Romanian, Russian, Simplified Chinese, Slovak, Spanish, Swedish, Tagalog, Thai, Traditional Chinese, Turkish, Ukrainian and Vietnamese.
LicenseProprietary software with Terms of Use
WebsiteInstagram.com


Àwọn Ìtọ́kasí


Tags:

Instagram Àwọn Ìtọ́kasíInstagramAmẹ́ríkàCristiano RonaldoFacebook

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Onome ebiNew JerseyÌsirò StatistikiSaadatu Hassan LimanOrílẹ̀ èdè AmericaÀjẹsára Bacillus Calmette–Guérin28 JuneBeirutMẹ́ksíkò2009Síńtáàsì YorùbáỌ̀rànmíyànKọ̀mpútà(211536) 2003 RR11OSI modelAbdullahi Ibrahim (ológun)ZDiamond JacksonÒrò àyálò YorùbáDapo AbiodunÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Ọjọ́ RúẸ̀bùn Nobel nínú Lítíréṣọ̀TOṣù Kínní 15Aderemi AdesojiISBNIyàrá ÌdánáIkúNew YorkLyndon B. JohnsonOrílẹ̀CaliforniaPópù SabinianÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáAustríàWikisourceYunifásítì HarvardAhmed Muhammad MaccidoIgbeyawo IpaAustrálíàAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéÈdè JavaJohn GurdonLinuxGbólóhùn Yorùbá30 MarchChinua AchebeKàlẹ́ndà GregoryOmiISO 3166-1 alpha-2Salvador AllendeRichard NixonÌlúAllwell Adémọ́lá🡆 More