Siẹrra Léònè

Siẹrra Léònè ( /siːˈɛrə liːˈoʊn/) (Krio: Sa Lone), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Siẹrra Léònè, je orile-ede ni Iwoorun Afrika.

O ni bode mo Guinea si ariwa ati ilaorun, Liberia ni guusuilaorun, ati Okun Atlantiki ni iwoorun ati guusuiwoorun. Sierra Leone ni aala ile to 71,740 km2 (27,699 sq mi) ao si ni olugbe ti idiye re je egbegberun 6.5. O je Imusin Britani tele, loni o ti di orile-ede olominira albagbepo to ni awon igberiko meta ati Western Area; awon wonyi na si tun je pipin si agbegbe merinla.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Siẹrra Léònè
Republic of Sierra Leone
Motto: "Unity - Freedom - Justice"
Location of Sierra Leone
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Freetown (1,070,200)
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaGeesi
Orúkọ aráàlúSierra Leonean
ÌjọbaConstitutional republic
• President
Julius Maada Bio
• Vice President
Mohamed Juldeh Jalloh
Independence
• from the United Kingdom
April 27 1961
• Republic declared
April 17 1971
Ìtóbi
• Total
71,740 km2 (27,700 sq mi) (119th)
• Omi (%)
1.0
Alábùgbé
• UN 2007 estimate
5,900,000 (103rd1)
• Ìdìmọ́ra
83/km2 (215.0/sq mi) (114th1)
GDP (PPP)2005 estimate
• Total
$4.921 billion (151st)
• Per capita
$903 (172nd)
Gini (2003)62.9
very high
HDI (2007) 0.336
Error: Invalid HDI value · 177th
OwónínáLeone (SLL)
Ibi àkókòUTC+0 (GMT)
Àmì tẹlifóònù232
ISO 3166 codeSL
Internet TLD.sl
1 Rank based on 2007 figures.

Sierra leone ni ojuojo olooru, pelu ile ayika to je orisirisi lati savannah de rainforests. Freetown ni oluilu, ilu totobijulo ati gbongan okowo re. Awon ilu pataki yioku na tun ni Bo, Kenema, Koidu Town ati Makeni.

Geesi ni ede onibise nibe, ti won unlo ni ile-eko, ibise ijoba ati latowo awon amohunmaworan. Mende ni ede gbangba ti won unso ni guusu, beesini Temne ni ede ti ariwa. Krio (ede Krioli lati inu ede Geesi ati opo awon ede Afrika to si je ede abinibi fun awon Krio Sierra Leone) ni ede akoko ti awon bi 10% olugbe unso sugbon bi 95% ni ede na ye. Botilejepe oun je lilo kakiri Sierra Leone, ede Krio ko ni ipo onibise kankan nibe.

Sierra Leone lonibise je ile fun awon eya eniyan merinla, ikookan won ni ede ati asa ti re. Awon eya eniyan titobijulo meji ni won wa, awon wonyi ni awon Mende ati awon Temne, ikokan won je 30% olugbe. Awon Mende poju ni agbegbe Guusu-Apailaorun Sierra Leone beesini awon Temne poju si ni Apaariwa Sierra Leone. O ti pe ti awon Mende ti un bori ninu oselu ni Sierra Leone. Opo awon omo-orile-ede je kiki elesin Musulumi, botilejepe won ni awon elesin Kristi bi 35%. Niyato si opo awon omo-orile-ede Afrikan miran, Sierra Leone ko ni isoro eya tabi esin bo se wa nibo miran.



Itokasi

Tags:

Constitutional republicGuineaLiberiaWest Africaen:Wikipedia:IPA for English

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Sigourney WeaverIfáÀsìá ilẹ̀ Bárbádọ̀sLahoreMamerto UrriolagoitiaSanusi Lamido SanusiISO 3166-1Nneka EzeigboSylvester MaduÈdè Gẹ̀ẹ́sìÌwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNUErin-Ijesha WaterfallsWikipediaPaul KehindeHTMLEmilio EstradaOrílẹ̀ èdè AmericaṢE (Idanilaraya)Mpumalanga12766 PaschenJoe BidenPópù Celestine 2kẸ̀tọ́-àwòkọEmperor Junna.bwEsther Oluremi ObasanjoR. Lee ErmeyMoky Makura67085 OppenheimerPornhubCorine OnyangoISO 4217Esther OyemaEpisteli Kejì sí àwọn ará Kọ́ríntìÌjọba àìlólóríOkey Bakassi.bbÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáRuth NeggaÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ Yorùbá4 (nọ́mbà)Adolf HitlerÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ FiẹtnámÌsopọ̀ kẹ́míkàOjúewé Àkọ́kọ́Nelson MandelaSTS-95Margaret Thatcher.mxRafael NúñezVieno Johannes Sukselainen10650 HoutmanÌdílé AugustaEwìJennie KimFósfórùGbenga AdefayeISBNRafeal Pereira Da SilvaỌ̀rọ̀ ìṣeÀrokò🡆 More