Oṣù Ṣẹ̀rẹ́

Oṣù Ṣẹ̀rẹ́ tàbí oṣù Kìíní jẹ́ oṣù àkọ́kọ́ nínú Kàlẹ́ńdà Gregory.

Ọjọ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni ó wà nínú osù yìí. Ọjọ́ kìíní ti oṣù Ṣẹ̀rẹ́ ni a ṣe ayẹyẹ ọdún títun. Ní ìpíndọ́gba, oṣù yìí sì jẹ́ oṣù tí ó máa ń tutú jù lọ ní ìdajì ayé àríwá (nítorí pé ó jẹ́ oṣù kejì ti ìgbà òtútù níbẹ̀); ó sì jẹ́ oṣù tí ooru máa ń mú jù lọ ní ìdajì ayé gúúsù (nítorí pé ó jẹ́ oṣù kejì ti ìgbà sọ́mà níbẹ̀). Ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, wọ́n pè é ní "January"; orúkọ yìí wá láti ọ̀rọ̀ èdè Látínì "iānuārius" (osù ti Janus). Nítorí èyí, ní èdè Yorùbá náà a sì máa ń pe oṣù yìí ní "oṣù Jánúárì" ní ìgbà mìíràn, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ ènìyàn máa ń wí pé kò yẹ́ kí a lò ó nítorí jíjẹ́ ọ̀rọ̀-àyálò tí ó jẹ́.

Oṣù Ṣẹ̀rẹ́
kalẹnda ti oṣu kini
Oṣù Kínní
Àìkú Ajé Ìsẹ́gun Ọjọ́rú Ọjọ́bọ̀ Ẹtì Àbámẹ́ta
1 2 3 4 5 6
7 8 9 10 11 12 13
14 15 16 17 18 19 20
21 22 23 24 25 26 27
28 29 30 31
 
2024
Osù:| Kínní | Kejì | Kẹta | Kẹrin | Kàrún | Kẹfà | Keje | Kẹjọ | Kẹ̀sán | Kẹ̀wá | Kọkànlá | Kejìlá

Tags:

Kalenda GregoryOsùÈdè Gẹ̀ẹ́sì

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ISO/IEC 9995ISO 10303-22Bọ́lá ÌgèISO 2014.tgISO 16750KúbàAmòfinDaniel KahnemanJosé Manuel PandoÒrìṣà EgúngúnISO 9897Biodun JeyifoISO 19092-1AṣọNational Basketball League (United States).ytBifid penisISO 31-3ISO 31-5King's College, LagosAtlantaFuel oilISO 31-0Oṣù KẹtaWNọ́rwèyDavid WoodardPópù Jòhánù 17kỌ́ksíjìnÀrokòLagos State Ferry Services CorporationÈdè JavaÌbòAyo AdesanyaÁfríkàA. Philip RandolphISO 3864Ẹkún ÌyàwóÀṣà YorùbáỌ̀rọ̀ ìṣeÀfin BeaumontOṣù KọkànláỌjọ́PrologAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ IpokiaMoroccoAfeez OwóOwe YorubaISO 639-1Adams OshiomholeISO 31-9Isaac NewtonJoel McHaleOníṣègùnIdriss DébyOlógbòBoolu-afesegbaGoogle.au.egSan FranciscoISO 14750IléMọ́remí Ájàṣoro.jp🡆 More