Kóstá Rikà (pípè /ˌkoʊstə ˈrikə/ ( listen)), lonibise o je Orile-ede Olominira ile Kosta Rika(Spánì: error: }: text has italic markup (help) tabi República de Costa Rica, pronounced ) je orile-ede ni Arin Amerika, o ni bode mo Nicaragua ni Ariwa, Panama ni ilaorun ati guusu, mo Okun Pasifik ni iwoorun ati guusu ati mo Omi-okun Karibeani ni ilaorun.
Orile-ede Olominira ile Kosta Rika Republic of Costa Rica [República de Costa Rica] error: {{lang}}: text has italic markup (help) | |
---|---|
Motto: "[Vivan siempre el trabajo y la paz] error: {{lang}}: text has italic markup (help)" (Spanish) "Long live work and peace" | |
Orin ìyìn: [Noble patria, tu hermosa bandera] error: {{lang}}: text has italic markup (help) (Spanish) Noble homeland, your beautiful flag 1 | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | San José |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Spani |
Lílò regional languages | Mekatelyu, Bribri |
Orúkọ aráàlú | Kóstá Rikà |
Ìjọba | Oseluarailu onilana-igbepapo (Orile-ede Olominira Oniaare) |
• Ààrẹ | Rodrigo Chaves Robles |
• Igbákejì Ààrẹ 1k | Stephan Brunner |
• Igbákejì Ààrẹ 2k | Mary Munive |
Aṣòfin | Iléìgbìmọ̀ Aṣòfin |
Ilominira Filole | |
• latowo Spein | September 15, 1821 |
• latowo Meksiko | October 4, 1824 |
• latowo UPCA | March 21, 1847 |
• Recognized by Spain | May 10, 1850 |
Ìtóbi | |
• Total | 51,100 km2 (19,700 sq mi) (128th) |
• Omi (%) | 0.7 |
Alábùgbé | |
• July 2009 estimate | 4,253,897 (123rd) |
• Ìdìmọ́ra | 85/km2 (220.1/sq mi) (107th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $48.881 billion |
• Per capita | $10,579 |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $29.318 billion |
• Per capita | $6,345 |
Gini (2007) | 48.0 Error: Invalid Gini value · 30th |
HDI (2007) | ▲ 0.854 Error: Invalid HDI value · 54th |
Owóníná | Costa Rican colón (CRC) |
Ibi àkókò | UTC-6 (CTZ) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | otun |
Àmì tẹlifóònù | +506 |
Internet TLD | .cr |
Kosta Rika, to tumosi "Eti Odo Olora", ti pa constitutionally ise ologun re re pelu ilana-ibagbepo ni 1949. Ohun nikan ni orile-ede Amerika Latini to wa ni akojo awon orile-ede 22 oseluarailu pipejulo. Kosta Rika lemolemo ti wa larin awon orile-ede Amerika Latini to gaju nipa Atoka Idagbasoke Eniyan, o si wa ni ipo 54th lagbaye ni odun 2007. O wa ni ipo keta lagbaye, ati akoko ni gbogbo Amerika, nipa Atoka Bi Ayika Se Wa ni 2010.
Ni 2007 ijoba Kosta Rikan sekede eto fun Kosta Rika lati di orile-ede ti ko lo karbon ni 2021. Gege bi New Economics Foundation se so, Kosta Rika gba ipo kinni ninu Atoka Planeti Adunnu beesi ni o je orile-ede "alawoewe julo" lagbaye.
Ki Columbus o to wa ibe ri awon omo abinibi ile Kosta Rika je apa were part of the Agbegbe Arin kariaye to budo si awon agbegbe idasa Mesoamerika ati Andes. Eyi ti je siodotun lati kopo ipa agbegbe Isthmo-Colombian. Ibi yi ni awon asa abinibi Mesoamerika ati Guusu Amerika ti pade.
Apa ariwaiwoorun orile-ede yi, Peninsula Nikoya, ni o je ibi guusujulo fun ipa asa Nahuatl nigbati awon olubori ara Spein de be ni orunddun kerindinlogun. Arin ati apaguusu orile-ede ni ipa Chibcha. Sibesibe, awon eniyan atilewa ti kopa lori asa Costa Rican odeoni niye to kere, nitoripe opolopo ninu won ku lowo awon arun bi smallpox ati idamu latowo awon alamusin ara spein.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Kóstá Rikà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.