Indonésíà

Indonésíà (pípè /ˌɪndoʊˈniːziə/ tàbí /ˌɪndəˈniːʒə/), lóníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Indonésíà (Àdàkọ:Lang-id), jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Gúúsùìlàorùn Ásíà àti Oseania.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Indonésíà
Republic of Indonesia

Republik Indonesia
Motto: Bhinneka Tunggal Ika  (Old Javanese)
Unity in Diversity

National ideology: Pancasila
Orin ìyìn: Indonesia Raya
Indonésíà
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Jakarta
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaIndonesian
Orúkọ aráàlúIndonesian
ÌjọbaOrile-ede olominira aare onipiparapo
• Aare
Joko Widodo
• Igbakeji Aare
Ma'ruf Amin
Ilominira 
leyin Dutch colonial rule
Ìtóbi
• Ilẹ̀
1,904,569 km2 (735,358 sq mi) (16k)
• Omi (%)
4.85
Alábùgbé
• 2009 estimate
229,965,000 (4k)
• 2000 census
206,264,595
• Ìdìmọ́ra
119.8/km2 (310.3/sq mi) (84k)
GDP (PPP)2010 estimate
• Total
$1,027.279 billion
• Per capita
$4,379
GDP (nominal)2010 estimate
• Total
$670.421 billion
• Per capita
$2,858
Gini (2002)34.3
medium
HDI (2007) 0.734
Error: Invalid HDI value · 111th
OwónínáRupiah (IDR)
Ibi àkókòUTC+7 to +9 (opo)
• Ìgbà oru (DST)
ko tele
Ojúọ̀nà ọkọ́òsì
Àmì tẹlifóònù+62
ISO 3166 codeID
Internet TLD.id

Indonesia ní àwọn erékùṣù 17,508. Pẹ̀lú olùgbé bíi 230 ẹgbẹgbẹ̀rún ènìyàn, òhun ni orílẹ̀-èdè olólùgbéjùlọ kẹrin láyé, ó sì ní olùgbé àwọn Mùsùlùmí tótóbijùlọ láyé. Indonésíà jẹ́ orílẹ̀-èdè olómìnira, pẹ̀lú aṣòfin àti ààrẹ adìbòyàn. Olúìlú rẹ̀ ni Jakarta. Ó ní bodè ilẹ̀ mọ́ Papua New Guinea, East Timor, àti Malaysia. Àwọn orílẹ̀-èdè míràn ìtòsí rẹ̀ náà tún ni Singapore, Philippines, Australia, àti ilẹ̀agbègbè Índíà Andaman and Nicobar Islands. Indonesia jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ olùdásílẹ̀ ASEAN àti ọmọ egbẹ́ Àwọn òkòwò únlá G-20.

Òṣùṣùerékùṣù Indonesia ti jẹ́ agbègbè òwò pàtàkì láti ọ̀rúndún keje, nígbàtí Srivijaya àti Majapahit ṣòwò pẹ̀lú Ṣáínà àti India. Díẹ̀díè àwọn olórí ibẹ̀ gba àpẹrẹ àṣà, ẹ̀sìn àti olóṣèlú láti òkèrè láti ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọ̀rúndún CE, bẹ́ẹ̀sìni àwọn ilẹ̀ọba Hindu àti Buddhisti gbòòrò. Itan Indonesia ti gba ipa latodo awon alagbara okere ti won wa sibe nitori awon ohun alumoni toni. Awon musulumi onisowo mu esin Islam wa sibe, beesini awon alagbara lati Europe ba ara won ja lati se adase owo ni awon Erekusu Spice Maluku lasiko Igba Iwari. Leyin awon orundun meta ati abo iseamusin awon ara Hollandi, Indonesia gba ilominira re leyin Ogun Agbaye 2k. Loni Indonesia je orile-ede olominira aare oniparapo to ni awon igberiko meta le logbon.

Kakiri awon opo erekusu re, Indonesia ni awon eya eniyan, ede ati esin otooto. Awon ara Java ni eya eniyan totobijulo, to si unbori loloselu. Indonesia ti sedagbasoke idamo kanna to ni ede orile-ede, orisi eya-eniyan, iseopo esin larin ogunlogo olugbe musulumi, ati itan iseamuin ati bi won se koju re.Motto orile-ede Indonesia, "Bhinneka Tunggal Ika" ("Okan ninu Opo"), tokasi awon opo orisirisi to da orile-ede yi. Botilejepe o ni olugbe pupo ati awon agbegbe sisupo ololugbe, Indonesia ni awon agbegbe aginju to ni opoelemin giga keji lagbaye. Botilejepe o ni awon ohun alumoni ile pupo aini unba ja gidigidi loni.

Orisun itumo oruko

Oruko Indonesia wa lati Latini Indus, ati Giriki nesos, to tumosi "erekusu". Oruko yi lojo lati orundun 18k, ki Indonesia alominra o to je didasile. Ni 1850, George Earl, onimo oro-eyaeniyan omo Geesi, damoran lilo oro Indunesians — ati Malayunesians — fun awon onibugbe "Osusuerekusu India tabi Osusuerekusu Malaya". Ninu iwe yi kanna, akeko Earl, James Richardson Logan, lo Indonesia gege bi oro-oruko kanna fun Osusuerekusu India. Sibesibe awon olukowe ara Hollandi ninuawon iwe lori East Indies won ko lo Indonesia. Dipo, won lo Osusuerekusu Malay (Maleische Archipel); the Netherlands East Indies (Nederlandsch Oost Indië), tabi Indië; Ilaorun (de Oost); ati Insulinde.

lati 1900, Indonesia bere sini wopo bi oruko ninu awon iwe olukowe lodi awon Nedalandi, beesini awon asetorile-ede gba ni lilo gege bi ifihan oselu. Adolf Bastian, lati Yunifasiti ilu Berlin, mugbajumo pelu iwe re Indonesien oder die Inseln des Malayischen Archipels, 1884–1894. Olukowe ara Indonesia to koko lo oruko yi ni Suwardi Suryaningrat (Ki Hajar Dewantara), nigbato da iso akede sile ni Nedalandi pelu oruko Indonesisch Pers-bureau ni 1913.

Itokasi

Tags:

ASEANAndaman and Nicobar IslandsAustraliaEast TimorJakartaList of countries by populationMalaysiaOceaniaPhilippinesRepublicSingaporeSoutheast Asiaen:WP:IPA for English

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

BobriskyAlfred Freddy KrupaGayD. O. FagunwaÌṣọ̀kan EuropeOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìLouis 13k ilẹ̀ FránsìBashar al-AssadẸgbẹ́ Dẹmọkrátíkì (USA)596 ScheilaEmperor Daigo28 JanuaryAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéÈdè JavaBillie HolidayWilliam Pitt the YoungerBaṣọ̀run GáàEmperor TakakuraMiguel MiramónEmperor KōmyōTiger WoodsTransnistriaDapo AbiodunÌlaòrùn ÁfríkàDavid CameronÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàAisha BuhariChristina Aguilera985 RosinaVincent EnyeamaArchibald HillIlẹ̀ Ọba Benin10 DecemberNọ́rwèyÌgbà Ìbíniàtijọ́Alfred KastlerLebanonHiroshimaInternetSurulereEllen Johnson SirleafRichard R. ErnstOdunlade AdekolaMorihiro HosokawaKarl Marx31 AugustHóséà Ayoola AgboolaBíbélì Mímọ́Deborah AbiodunKikan Jesu mo igi agbelebuÈdè Ítálì14 August.csNigerian People's PartyUju UgokaMa Ying-jeouWarsawUgepẸgbẹ́ kọ́múnístìFẹlá Kútì🡆 More