Argẹntínà

ArgẹntínàNínú ètò ìkànìyàn 1995, iye àwọn ènìyàn tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Ajẹntínà (Argentiana) lé díẹ̀ ní mílíọ̀nù mẹ́rìnlélógójì àti àti ààbọ̀ (46 245 668).

Èdè Pànyán-àn ni èdè tí wọ́n fi ń ṣe ìjọba ní ibẹ̀. Àwọn èdè mìíràn tí wọ́n tún ń sọ ní orílè-èdè yìí lé ní ogún. Lára àwọn ogún èdè yìí ni àwọn èdẹ̀ tí wọ́n ń pè ní Àmẹ́rídíánà (Ameridian Languages) wà. Ara àwọn èdè. Àmérídíánà yìí ni ‘Guarani, Araucanian, Metaco àti Quechua’. Àwọn èdè tí ó tún wà lára ogún yìí ni èdè tí àwọn tí ó wá se àtìpó ń sọ. Lára wọn ni èdè Ítílì (Ìtahàn) àti Jámánì (Herman). Èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbilẹ̀ sí i ní orílẹ̀-èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè fún òwò àgbáyé àti èdè àwọn tí ó ń ṣe àbẹ̀wò wá sí ibẹ̀ (International trade and tourism). Wọ́n ń lo èdè Gẹ̀ẹ́sì yìí pẹ̀lú èdè Pànyán-àn.

Argentine Republic

República Argentina
Motto: En unión y libertad
"In Unity and Freedom"
Orthographic projection of Argentina
Orthographic projection of Argentina
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Buenos Aires
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaSpanish
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
86.4% European (mostly Italian and Spanish)
8% Mestizo
4% Arab and East Asian
1.6% Amerindian
Orúkọ aráàlúArgentine, Argentinian, Argentinean
ÌjọbaFederal presidential republic
• President
Javier Milei
• Vice President
Victoria Villarruel
• Supreme Court President
Horacio Rosatti
Independence 
from Spain
• May Revolution
25 May 1810
• Declared
9 July 1816
Ìtóbi
• Total
2,766,890 km2 (1,068,300 sq mi) (8th)
• Omi (%)
1.1
Alábùgbé
• 2022 estimate
46 245 668 (33rd)
• 2011 census
40 117 096
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$572.668 billion (23rd)
• Per capita
$14,408 (57th)
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$324.767 billion (31st)
• Per capita
$8,171 (66th)
Gini (2006)49
Error: Invalid Gini value
HDI (2006) 0.860
Error: Invalid HDI value · 46th
OwónínáPeso (ARS)
Ibi àkókòUTC-3 (ART)
• Ìgbà oru (DST)
UTC-2 (ART)
Ojúọ̀nà ọkọ́right (trains ride on the left)
Àmì tẹlifóònù+54
Internet TLD.ar
Argẹntínà
Salta

Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Steve JobsEmperor Go-En'yūLebanonEewo ninu awon igbagbo YorubaẸgbẹ́ Ìgbìmọ̀ Torile-ede ÁfríkàNecmettin ErbakanIsuikwuatoCharlize TheronInternetOṣù Kínní 15Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ KóngòXÈdè iṣẹ́ọbaNẹ́dálándìC++LèsóthòÀjàkáyé-àrùnIbi Ọ̀ṣọ́ ÀgbáyéElisabeti Kejì17 MayRómùJohn DiefenbakerTiger WoodsÀdírẹ́ẹ̀sì IPBerlinÌṣe Òfin àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú 1964PakístànEmperor KōmyōIgbó OlodùmarèGuatemalaOṣù Kínní 30K1 De UltimateÌwéìròyìnÌran YorùbáRichard R. ErnstNitrogenAaliyahTai SolarinMontenegroBoolu-afesegba28 JanuaryBetty ShabazzWikisourceShirley ChisholmEmperor SujinEmperor Go-MomozonoÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ àwọn FilipínìDresdenỌjọ́ 18 Oṣù KẹtaẸ̀sìn IslamEmperor Go-ShirakawaCentral Intelligence AgencyWeb browserUrhoboMájẹ̀mú LáéláéOluwatoyosi OgunseyeÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Bùlgáríà18 August🡆 More