Tànsáníà tabi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìṣọ̀kan ilẹ̀ Tànsáníà (pípè /ˌtænzəˈniːə/; Swahili: Jamhuri ya Muungano wa Tanzania) je orile-ede ni Ilaoorun Afrika to ni bode mo Kenya ati Uganda ni ariwa, Rwanda, Burundi ati orile-ede Olominira Toseluarailu ile Kongo ni iwoorun, ati Zambia, Malawi ati Mozambique ni guusu.
Awon bode Tansania ni ilaorun ja si Okun India.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìṣọ̀kan ilẹ̀ Tànsáníà United Republic of Tanzania Jamhuri ya Muungano wa Tanzania (Swahili) | |
---|---|
Motto: "Uhuru na Umoja" (Swahili) "Freedom and Unity" | |
Olùìlú | Dodoma (de jure) |
Ìlú tótóbijùlọ | Dar es Salaam |
Official Language | |
National Language | Swahili |
Orúkọ aráàlú |
|
Ìjọba | Unitary dominant party presidential constitutional republic |
Samia Hassan Suluhu | |
• Vice-President | Vacant |
• Prime Minister | Kassim Majaliwa |
• Speaker | Job Ndugai |
• Chief Justice | Ibrahim Hamis Juma |
Aṣòfin | National Assembly |
Independence from the United Kingdom | |
9 December 1961 | |
• Unguja and Pemba | 10 December 1963 |
• Merger | 26 April 1964 |
• Current constitution | 25 April 1977 |
Ìtóbi | |
• Total | 947,303 km2 (365,756 sq mi) (31st) |
• Omi (%) | 6.4 |
Alábùgbé | |
• Àdàkọ:UN Population estimate | Àdàkọ:UN PopulationÀdàkọ:UN Population (25th) |
• 2012 census | 44,928,923 |
• Ìdìmọ́ra | 47.5/km2 (123.0/sq mi) |
GDP (PPP) | 2019 estimate |
• Total | $186.060 billion |
• Per capita | $3,574 |
GDP (nominal) | 2019 estimate |
• Total | $61.032 billion |
• Per capita | $1,172 |
Gini (2012) | 37.8 medium |
HDI (2018) | ▲ 0.528 low · 159th |
Owóníná | Tanzanian shilling (TZS) |
Ibi àkókò | UTC+3 (EAT) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left |
Àmì tẹlifóònù | +255 |
ISO 3166 code | TZ |
Internet TLD | .tz |
|
Awon agbegbe Tanzania niwonyi: Arusha · Dar es Salaam · Dodoma · Iringa · Kagera · Kigoma · Kilimanjaro · Lindi · Manyara · Mara · Mbeya · Morogoro · Mtwara · Mwanza · Pemba North · Pemba South · Pwani · Rukwa · Ruvuma · Shinyanga · Singida · Tabora · Tanga · Zanzibar Central/South · Zanzibar North · Zanzibar Urban/West
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Tanzania, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.