Orílẹ̀-èdè Olómìnira Zambia (pípè /ˈsæmbiə/) jẹ́ Orílẹ̀-èdè tileyika kan ni Apaguusu Afrika.
Awon Orílẹ̀-èdè tó súnmọ ni Orílẹ̀-èdè Olómìnira Toseluarailu ile Kongo ní àríwá , Tanzania ni ariwa-ilaorun, Malawi ni ilaorun, Mozambique, Zimbabwe, Botswana, ati Namibia ni guusu, ati Angola ni iwoorun. Oluilu re ni Lusaka, tó bùdó sí apá gúúsù-arin ibe.
Republic of Zambia | |
---|---|
Motto: "One Zambia, One Nation" | |
Orin ìyìn: Stand and Sing of Zambia, Proud and Free | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Lusaka |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Gẹ̀ẹ́sì |
Lílò regional languages | Nyanja, Bemba, Lunda, Tonga, Lozi, Luvale, Kaonde. |
Orúkọ aráàlú | Zambian |
Ìjọba | Orile-ede olominira |
• Ààrẹ | Hakainde Hichilema |
• Igbákejì Ààrẹ | Mutale Nalumango |
Ilominira latowo Iparapo Ileoba | |
• Date | 24 October 1964 |
Ìtóbi | |
• Total | 752,618 km2 (290,587 sq mi) (39th) |
• Omi (%) | 1 |
Alábùgbé | |
• 2009 estimate | 12,935,000 (71st) |
• 2000 census | 9,885,591 |
• Ìdìmọ́ra | 17.2/km2 (44.5/sq mi) (191st) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $18.454 billion |
• Per capita | $1,541 |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $13.000 billion |
• Per capita | $1,086 |
Gini (2002–03) | 42.1 medium |
HDI (2007) | ▲ 0.434 Error: Invalid HDI value · 165th |
Owóníná | Zambian kwacha (ZMK) |
Ibi àkókò | UTC+2 (CAT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+2 (not observed) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | òsì |
Àmì tẹlifóònù | 260 |
ISO 3166 code | ZM |
Internet TLD | .zm |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Zambia, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.