Wiki Yorùbá

Adeniran Ogunsanya QC, SAN (31 January 1918 – 22 November 1996) jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú Ibadan Peoples Party (IPP).

Ojúewé Àkọ́kọ́
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fún Ìpínlẹ̀ Èkó ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kejì. Òun náà tún ni alága pátá pátá fún ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian People's Party nígbà ayé rẹ̀. Wọ́n bí Adéníran ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kíní ọdún 1918 ní agbègbè ÌkòròdúÌpínlẹ̀ Èkó sí agboolé ọmọ Ọba Sùbérù Ògúnsànyà Ògúntádé tí ó jẹ́ Ọdọ̀fin ti ìlú Ìkòròdú nígbà náà. Adéníran lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Hope Waddell Training Institute ní ìlú Calabar nígbà tí ó ń gbé pẹ̀lú àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìlú Calaba. Ìjọba fi ẹ̀bùn ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ dá Adéníra lọ̀lá láti kàwé síwájú si ní ilé-ẹ̀kọ́ King's College tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó látàrí bí ó ṣe peregedé jùlọ pẹ̀lú máàkì tí ó ga jùlọ nínú ìdánwò àṣekágbá ti Standard VI (6) ní ọdún 1937. Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti University of Manchester àti Gray's Inn tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin.

(ìtẹ̀síwájú...)

Ojúewé Àkọ́kọ́
Àsìá ilẹ̀ Zimbabwe
Àsìá ilẹ̀ Zimbabwe

Ọjọ́ 18 Oṣù Kẹrin: Independence Day ni Zimbabwe (Àsìá) (1980).

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...

Àwọn aláìsí lóòní...

Ọjọ́ míràn: 1617181920 | ìyókù...
Ojúewé Àkọ́kọ́
Ojúewé Àkọ́kọ́
Ojúewé Àkọ́kọ́

Ojúewé Àkọ́kọ́ Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì
Èdè

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

MicrolophusOSI modelISO 9ISO 9660ISO 10303ISO 15189Celestial Church of ChristÒjò.vgẸ̀gbà ỌrùnFrancisco Diez CansecoSístẹ̀mù ÒrùnISO 4157ISO 3864Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ BidaPablo PicassoÌgbà EléèédúÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàISO 11992ẸrankoISO 9126ISO 14971Adeniran OgunsanyaBostonPópù Adrian 5kAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ IpokiaISO/IEC 8859-6Bíbélì Mímọ́ISO 15924Ahmose 1kJohn LewisÌbò2019 wiwo ile-iwe ni EkoỌkùnrinISO 13567ÌṣíròHimachal PradeshShoe sizeISO 14644-818 JuneISO/IEC 7811PennsylvaniaECMAScriptÈdè Ìṣèlànà Kọ̀mpútàÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáISO 19011Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin ÁfríkàJ. Mohammed ManaISO 31-5John HowardUISO 10303-28HorsepowerOlógbòNọ́rwèyIowaISO/IEC 8859-1Marie-Joseph Motier, Marquis de Lafayette3169 OstroKọ́nsónántì èdè YorùbáBaskin-RobbinsISO 14644-7ISO 31-13Iwoorun AfrikaGabriel TerraISO 7002ISO 732ISO 15919JBIGỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Alizé CornetRita HayworthAbdullah Kejì ilẹ̀ Jọ́rdánì.be🡆 More