Mathimátíkì: MATIMÁTÌSÌ

Mathematiki tabi Ìmọ̀ Ìsirò jẹ́ èyí t'on jẹ mo nipa ọ̀pọ̀iye (quantity), nipa òpó (structure), nipa iyipada (change) ati nipa ààyè (space).

Idagbasoke imo Isiro wa nipa lilo àfòyemọ̀ọ́ (abstraction) ati Ọgbọ́n ìrọ̀nú, pelu onka, isesiro, wíwọ̀n ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri (shapes) ati bi won se n gbera (motion). E ni awon Onimo Isiro n gbeyewo, ero won ni lati wa aba tuntun, ki won o si fi ootọ́ re mulẹ̀ pelu itumo yekeyeke.

Mathimátíkì: MATIMÁTÌSÌ
Agbègbè tí a tí nko èkó ìsirò ti ile-èkó èkósé owó ti modèle de Galton-Watson.

Mathimátíkì: MATIMÁTÌSÌ

A n lo Imo Isiro ka kiri agbaye ni opolopo ona ninu Imo Sayensi, Imo Ise Ero, Imo Iwosan, ati Imo Oro Okowo. Eyi je mo eko imo isiro to ko ti ni ilo kankan bo tileje pe o se se ki a wa ilo fun ni eyinwa ola.



Àwon Itoka si

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Lalisa ManobalÒrò àyálò YorùbáIonuț Silaghi de OasDÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020ISO 5776George ReadISO 15686ISO 13490Sheraton Lagos HotelÌṣèlú ilẹ̀ GuineaISO/IEC 8859-5BostonDavid Ibiyeomie.bsÌṣírò918 IthaISO/IEC 11404.inỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)ISO/IEC 38500ISO/IEC 20000ISO 9RáràỌkùnrinCôte d'IvoireISO 3166-3New YorkISO 9660Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004Benue-Plateau StateÈdè Ìṣèlànà Kọ̀mpútàISO 639Salvador, BahiaKISO 259ISO/IEC 8859-15GánàMarcelo Azcárraga PalmeroBeirutISO 9126Facebook16 JuneOrílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin ÁfríkàHimachal PradeshIṣẹ́ Àgbẹ̀ ní NàìjíríàNàìjíríàFinidi GeorgeISO/IEC 11179ISO 6902022Èdè TàmilKúbà.nlÀkàyéOyunSilvio BerlusconiISO 31000Celestial Church of ChristOwóISO 7736Àwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáOgun Àgbáyé KìíníJohann Wolfgang von GoethePrologInternational Organization for StandardizationECMAScriptAalo oòrùn àti osupaMogadishuTallinn🡆 More