Mọ́skò

Mọsko ni olú-ìlú Rọ́síà.

Ìlú nlá ni. Orí odò Moskva ni ó wà. Odún 1918 ni ó di olú-ìlú USSR nígbà tí wón gbé olú-ìlú yìí kúrò ní Leningrad. Moscow ni ìlú tí ó tóbi jù ní Rósíà. Oun ni ó wà ní ipò kefà tí a bá ní kí á ka àwon ìlú tí ó tóbi ní ilé-ayé. Ìlú tí ó léwà ni Moscow. Uspenki Cathedral tí ó wà ní ibè ni wón ti máa n dé àwon tsar (àwon olùdarí Rósíà) lade láyé àtijó. Ibè náà ni Arkhangelski tí wón ti n sin wón wà. Ilé-isé àti Ilé-èko pò ní ibè Lára àwon ilé-èkó ibè ni. Lomonosov University tí ó jé University ìjoba wa ni ibe. Orí òkè Lenin ni wón kó o sí òun sì ni University tí ó tóbi jù ní Rósíà. Ibè náà ni USSR Academy of Sciences wa. Mùsíómù, ilé-ìkàwé àti tíátà wà níbè. Àwon Bolshoi Theatre and Ballet, the State Symphony Ochestra àti the State Folk Dance Company tí ó wà ni Moscow gbayì gan-an ni.

Mọsko
Red Square
Red Square
Area
 • Total1,081 km2 (417 sq mi)
Population
 • Total12,382,754





Itokasi

Tags:

Rọ́síà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

.nlFile Transfer ProtocolBritish standard pipe thread135 film.ytArméníà.suÌwé-òfin Ìbágbépọ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàMalcolm FraserOjúewé Àkọ́kọ́Quett MasireẸranSARS-CoV-2James ScullinKúbàISO 428ISO 31-7Pọ́rtúgàlNebraskaÈdè ÁrámáìkìUSAISO 14644-9Àwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàẸ̀gbà ỌrùnUnited Nations Development ProgrammePópù Innocent 7kISO 19114DeutschlandliedISO 19092-1John LewisÀtòjọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Mẹ́ksíkòỌ̀rọ̀ayéijọ́unOperating System3169 OstroISO/IEC 7813ISO/TR 11941AbrahamuISO/IEC 17025Àdìtú OlódùmarèWikimediaAlizé CornetISO 9984Iwoorun AfrikaISO 6438.rwGhanaISO/IEC 27000-seriesSebastián PiñeraMPEG-21ISO 690King's College, LagosISO/IEC 11179.noArno Allan Penzias.rsBòlífíàBàrbúdàỌbàtáláTitun Mẹ́ksíkòMichael JordanBrasil31 MayISO 732Queen's CounselÀṣà NokAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ BidaTony ElumeluOSI modelG🡆 More