Kẹ́nyà tàbí Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyà je orile-ede ni Ìlaòrùn Áfríkà.
O dubule si eba Okun India, ni agedemeji aye, Kẹ́nyà ni bode mo Ethiópíà (ariwa), Sòmálíà (ariwailaorun), Tànsáníà (guusu), Ùgándà ati Lake Victoria (iwoorun), ati Orile ede Gúúsù Sudan (ariwaiwoorun). Oluilu re ni Nairobi. Awon onibugbe ibe ti po to 38 legbegberun.
Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyà Republic of Kenya Jamhuri ya Kenya (Swahili) | |
---|---|
Motto: "Harambee" (Swahili) "Let us all pull together" | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Nairobi 1°16′S 36°48′E / 1.267°S 36.800°E |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | |
National language | Swahili |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2019) |
|
Ẹ̀sìn (2019) | Àdàkọ:Ublist |
Orúkọ aráàlú | Kenyan |
Ìjọba | Unitary presidential constitutional republic |
• Ààrẹ | Uhuru Kenyatta |
• Ìgbákejì Ààrẹ | William Ruto |
• Speaker of the Senate | Kenneth Lusaka |
• Speaker of the National Assembly | Justin Muturi |
• Chief Justice | David Maraga |
• Attorney General | Paul Kihara Kariuki |
Aṣòfin | Parliament |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | Senate |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | National Assembly |
Independence | |
• from the United Kingdom | 12 December 1963 |
• Republic declared | 12 December 1964 |
Ìtóbi | |
• Total | 580,367 km2 (224,081 sq mi) (48th) |
• Omi (%) | 2.3 |
Alábùgbé | |
• 2019 census | 47,564,296 (29th) |
• Ìdìmọ́ra | 78/km2 (202.0/sq mi) (124th) |
GDP (PPP) | 2020 estimate |
• Total | $206.532 billion |
• Per capita | $4,071 |
GDP (nominal) | 2020 estimate |
• Total | $109.116 billion |
• Per capita | $2,151 |
Gini (2014) | 42.5 medium · 48th |
HDI (2018) | ▼ 0.579 medium · 147th |
Owóníná | Kenyan shilling (KSH) |
Ibi àkókò | UTC+3 (EAT) |
Irú ọjọ́ọdún | dd/mm/yy (AD) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left |
Àmì tẹlifóònù | +254 |
Internet TLD | .ke |
According to the CIA, estimates for this country explicitly take into account the effects of mortality because of AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex, than would otherwise be expected. |
Kenya pinsi awon igberiko 8 ti olori won n je Alakoso Igberiko (Aare lo n yan won). Awon igberiko wonyi (mkoa singular mikoa plural in Swahili) na tun je pinpin si awon ibile (wilaya). Awon ibile 69 lo wa. Awon ibile wonyi na tun je pipin si awon ipinsi 497 (taarafa). Awon ipinsi tu je pipin si 2,427 awon ibudo 2,427 (mtaa) ati omo ibudo 6,612 (mtaa mdogo).. Awon igberiko na niwonyi:
Ilu | Iye eniyan |
---|---|
Nairobi | 2 940 911 |
Mombasa | 707 400 |
Nakuru | 337 200 |
Kisumu | 273 400 |
Eldoret | 249 100 |
Nyeri | 213 000 |
Machakos | 179 500 |
Meru | 140 900 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Wiki Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Kenya |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Kenya, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.