Japan

Japan (日本, Nihon or Nippon?, officially 日本国 Nippon-koku tabi Nihon-koku) jẹ́ orílẹ̀-èdè erékùṣù ní Ìlà Oòrùn Asia.

Ó pàlà pẹ̀lú Òkun Pàsífíìkì, o wa ni ilaorun Okun Japan, Saina, Ariwa Korea, Guusu Korea ati Rosia, o gun lati Okun Okhotsk ni ariwa de Okun Ilaorun Saina ati Taiwan ni guusu. Awon leta ti won fi n ko oruko Japan tumo si "orisun orun", eyi lo je idie ti a fi n pe Japan ni "Ile Iladide Orun".

Japan

Shinjitai: 日本国
Kyujitai: 日本國

Nippon-koku or Nihon-koku
Orin ìyìn: Kimigayo (君が代?)
Government Seal:
Seal of the Office of the Prime Minister and the Government of Japan
Paulownia (五七桐 Go-Shichi no Kiri?)
Location of Japan
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Tokyo (de facto)
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaNone
Lílò regional languagesAynu itak, Eastern Japanese, Western Japanese, Ryukyuan, and several other Japanese dialects
National language

National Scripts


Japanese

Kanji
Hiragana
Katakana
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
98.5% Japanese, 0.5% Korean, 0.4% Chinese, 0.6% other
Orúkọ aráàlúJapanese
ÌjọbaParliamentary democracy with constitutional monarchy
• Emperor
Naruhito (徳仁)
Fumio Kishida (岸田 文雄)
AṣòfinNational Diet
• Ilé Aṣòfin Àgbà
House of Councillors
• Ilé Aṣòfin Kéreré
House of Representatives
Formation
• National Foundation Day
February 11, 660 BC
• Meiji Constitution
November 29, 1890
• Current constitution
May 3, 1947
• Treaty of
San Francisco

April 28, 1952
Ìtóbi
• Total
377,975 km2 (145,937 sq mi) (61st)
• Omi (%)
1.4
Alábùgbé
• 2021 estimate
125,600,000 (10th)
• 2020 census
126,226,568
• Ìdìmọ́ra
334/km2 (865.1/sq mi) (24th)
GDP (PPP)2021 estimate
• Total
$5.586 trillion (3rd)
• Per capita
$32,608 (23rd)
GDP (nominal)2021 estimate
• Total
$5.378 trillion (3rd)
• Per capita
$44,928 (23rd)
Gini38.1 (2002)
Error: Invalid Gini value
HDI (2007) 0.960
Error: Invalid HDI value · 10th
OwónínáInternational Symbol ¥ Pronounced (Yen)
Japanese Symbol 円 (or 圓 in Traditional Kanji) Pronounced (En) (JPY)
Ibi àkókòUTC+9 (JST)
• Ìgbà oru (DST)
not observed
Irú ọjọ́ọdúnyyyy-mm-dd
yyyy年m月d日
Era yy年m月d日 (CE−1988)
Ojúọ̀nà ọkọ́left
Àmì tẹlifóònù81
ISO 3166 codeJP
Internet TLD.jp

Japan jẹ́ arkipelago àwọn Erékùṣù 6,852. àwọn erékùṣù ibẹ̀ tí ó tóbi jùlọ ní Honshū, Hokkaidō, Kyūshū àti Shikoku, ti àpapọ̀ wọ́n jẹ́ èdè mẹ́tàdínlọ́gọ́rùún (97%) ìtóbi ilẹ̀ Japan. Opo awon erekusu wonyi je oloke, opo je onileru; fun apere, ibi gigajulo ni Japan, Oke Fuji, je onileru. Japan je orile-ede ikewa to iye awon eniyajulo, pelu awon eniyan ti won to egbegberun 128. Agbegbe Titobiju Tokyo, to ni oluilu de facto Tokyo ati awon ibile ayika re, ni o je agbegbe metropoli titobijulo lagbaye pelu iye eniyan to to egbegberun 30.

Iwadi iseoroayeijoun fihan pe awon eniyan ti ungbe ni Japan lati igba to ya bi igba Okutaijoun Oke. Igba akoko ti a ko gbo nipa oruko Japan ninu iwe akoole je ninu awon iwe itan Saina lati orundun 1k SK. Ipa latodo awon orile-ede miran je titele pelu idagbe igba pipe bo se han gbangba ninu itan Japan. Ni igbeyin orundun 19k ati 20k ijabori ninu Ogun Saina ati Japan Akoko, Ogun Rosia Japan, ati Ogun Agbaye 1k gba Japan laye lati fe ile re nigba itoja ogun. Ogun Saina ati Japan Keji odun 1937 tan titi de Ogun Agbaye 2k, to wa sopin ni 1945 leyin ijubombu atomu si Hiroshima ati Nagasaki. Lati igba atunse ibagbepo re ni 1947, Japan ti di oba onibagbepo olokan pelu obaluaye atiileasofin aladiboyan tounje Diet mu.

Alagbara itokowo ninla, Japan ni o ni itokowo keta totobijulo lagbaye gegebi GIO oloruko ati gegebi ifiwe agbara iraja. Bakanna o tun je atajalode kerin titobijulo ati arajalatode kerin titobijulo lagbaye. Botilejepe Japan lonibise ti jowo eto re lati gbe ogun, o di ile-ise ologun odeoni mu fun abo ati ise alafia. Leyin Singapore, Japan lo ni ipaniyan to kerejulo lagbaye. Gegebi UN ati WHO se diye, Japan lo ni ireti igbeaye gigunjulo larin gbogbo awon orile-ede lagbaye. Bakanna o tun ni iku omo-owo tokerejulo keta, gegebi UN se so.



Itokasi

Tags:

East AsiaJa-nippon nihonkoku.oggJa-nippon_nihonkoku.oggNorth KoreaPacific OceanPeople's Republic of ChinaRussiaSouth KoreaTaiwan

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Mandy PatinkinÈdè Gẹ̀ẹ́sì.рфBukunmi OluwasinaOhun ìgboroNàìjíríà20242828 Iku-TursoShoshenq 6kHeinrich RohrerÌjọba àìlólóríSt. John's (Ántígúà àti Bàrbúdà)Pópù Celestine 2kMarcel ProustKárbọ̀nùÀdírẹ́ẹ̀sì IPIlẹ̀ọba Aṣọ̀kan Nẹ́dálándìInternetÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Côte d'IvoireÀìsàn ẹ̀jẹ̀ ríruGbenga AdefayeÀjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní àwọn Erékùṣù KánárìItoro Umoh ColemanẸ̀wádún 2010STS-95ṢE (Idanilaraya)Juan Esteban PederneraT. M. AlukoEmperor Seiwa4 (nọ́mbà)ÍndíàWikipediaÀwọn èdè Índíà-EuropeHassiomuManuel Benito de CastroPaul Kehinde14 May.bb.tnRwandaÌránìÀrokò.uyAustrálíàISO 4217EhoroKunle AfolayanNneka EzeigboGoogleMustapha IsmailCorine OnyangoJim CourierGrace EborOruchuban EbichuÌtàn ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàlLCarl Johan Thyselius2882 TedescoJapanRamesses 7kPonun StelinVieno Johannes SukselainenMariah Carey7 May67085 OppenheimerAtlanta3471 AmelinErin-Ijesha WaterfallsJoseph Addison🡆 More