Ikọ́ jẹ́ ọ̀nà gbígbé atẹ́gùn jáde pẹ̀lú agbára láti ọ̀nà ọ̀fun kí a lè fọ ọ̀nà ọ̀fun náà mọ́ kúrò lọ́wọ́ ìdọ̀tí tí ó sá pamọ́ síbẹ̀.
Ikọ́ wíwú lè jẹ́ lẹ́ẹ̀kan tàbí léra-léra tí yóò sì mú kẹ̀lẹ̀bẹ̀ dání. Wíwúkọ́ léra-léra lè túmọ̀ sí wípé àìsàn tàbí àrùn kan wà ní àgọ́ ara nítorí wípé púpọ̀ lára àwọn àrùn àgọ́ ara ni a lè tàn kálẹ̀ tàbí pin fún ẹlòmíràn
Ṣíṣe ìtọ́jú ikọ́ nííṣe pẹ̀lú wíwádí ohun tí ó fa ikọ́ fúnra rẹ̀, bí a bá ti mọ̀ọ́n, ìtọ́jú rẹ̀ yóò yá kánkán.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ikọ́, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.