Egbe Ipapo Kariaye Ajose Boolu-Elese (Geesi:International Federation of Association Football; Faranse: Fédération Internationale de Football Association), to gbajumo gege bi FIFA, ni is the international agbarajo asejoba kariaye fun boolu-elese.
Ibujoko re wa ni Zürich, Switzerland, be sini Aare re lowolowo bayi ni Sepp Blatter. FIFA ni o ni ojuse fun agbajo ati isejoba awon idije pataki boolu-elese, agaga Ife Eye Agbaye FIFA, to waye lati odun 1930.
Fédération Internationale de Football Association | |
---|---|
Motto | For the Game. For the World |
Ìdásílẹ̀ | May 21, 1904 |
Type | Sports federation |
Ibùjókòó | Zürich, Switzerland |
Ọmọẹgbẹ́ | 208 national associations |
Official languages | English, French, German, Spanish, |
President | Sepp Blatter |
Website | www.fifa.com |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article FIFA, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.