Físíksì (lati inu Ìmọ̀ aláàdánidá) tabi Fisiki (Physics) jẹ́ ìmọ̀ sáyẹ́nsì tí ó ń ṣe ìwádí èlò ati awon okun ti won n je sise akiyesi ninu àdánidá.
Awon onímọ̀ aláàdánidá n se iwadi isise ati awon ohun-ini eda aye to yi wa ka lati àwọn ẹ̀yà ara ti won n se gbogbo awon elo ti a mo (Ìmọ̀aláàdánidá ẹ̀yà ara, particle physics) titi de bi àgbàlá-ayé se n wuwa bi odidi kan (ìmọ̀ìràwọ̀títò astronomy, ìmọ̀ìdáyé cosmology).
Ise imo aladanida ni lati wa awon ofin ijinle ti gbogbo awon ohun aladanida n tele.
Ko si iye igbedanwo to le fi han pe iro mi je tito, sugbon igbedanwo kan pere le fihan wipe o je aito – Albert Einstein
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Físíksì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.