Òṣùpá

Òṣùpá (aami: ) jẹ́ olùyípo (satellite) ilẹ̀-Ayé.

Arinidaji jíjìnnà sí láti ilẹ̀-ayé títí dé orí òṣùpá jẹ́ kìlómítà 384,403. Ìwọ̀n ìdábùú òbírí yìí fi ìlọ́pò ọgbọ̀n jù ti ilẹ̀-ayé. Ìlà-àárín òṣùpá jẹ́ kìlómítà 3,474 - tó jẹ́ pé díẹ̀ ló fi jù ọ̀kan nínú mẹ́rin lọ sí ti ilẹ̀-ayé. Èyí sì jẹ́ pé kíkún-inú (volume) òṣùpá jẹ́ ìdá àádọ́ta péré ti ilẹ̀-ayé. Fífà ìwúwosí rẹ̀ jẹ́ ìdá mẹ́fà sí ti ilẹ̀-ayé. Òṣùpá ń yípo ilẹ̀-ayé ní ẹ̀ẹ̀kan láàárín ọjọ́ 27.3 (1 oṣù; ọjọ́ mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ó lé ní wákàtí mẹ́ta).

Òṣùpá
Òṣùpá
Òṣùpá
Òṣùpá ati Ilé-ayé


Itokasi

Tags:

AyéOṣù

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

.bwIfáNnamdi AzikiweṢE (Idanilaraya)Ruth NeggaÌpínlẹ̀ Ọ̀yọ́Nneka EzeigboWiki13 OctoberGbenga AdefayeEre idarayaMambilla PlateauEmperor JunnaRafeal Pereira Da Silva14 MayUttar PradeshÈdè Gẹ̀ẹ́sì67085 OppenheimerÀìsàn ẹ̀jẹ̀ ríruÌránìBalogun MarketOlógbòLahoreIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanÀjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní àwọn Erékùṣù KánárìAkanlo-edeMoky MakuraSalif Keita (footballer)GoogleISO 1020610650 HoutmanÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Côte d'IvoireOkey BakassiGómìnàDọ́là àwọn Erékùṣù Káímàn.рфItoro Umoh ColemanAlain PoherMpumalangaÀwọn ará Jẹ́mánìHassiomuJennie Kim22 FebruaryEsther OnyenezideYinka AjayiIṣẹ́ Àgbẹ̀ISO 4217Erin-Ijesha WaterfallsHéctor José CámporaÒgún LákáayéEmilio EstradaT. M. AlukoỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Vincent EnyeamaÀwọn Erékùṣù ChathamGrace EborTsung-Dao LeeÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Báháráìnì2 DecemberApágúúsù EuropeMikhail YouzhnyLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Àsìá ilẹ̀ Bẹ̀rmúdàJim Courier.tnLionel JospinÈdè Lárúbáwá🡆 More