2°22′23″E / 29.5734571°N 2.3730469°E / 29.5734571; 2.3730469
Àlgéríà (Arabiki: الجزائر, al-Gazā’ir), fun onibise Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú àwọn Ènìyàn ilẹ̀ Àlgéríà, je orile-ede ni Àríwá Áfríkà. Ile re ni ti orile-ede ti o tobijulo ni Okun Mediterraneani, ekeji totobijulo ni orile Áfríkà leyin Sudan, ati ikokanla totobijulo lagbaye.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú àwọn Ènìyàn ilẹ̀ Àlgéríà People's Democratic Republic of Algeria الجمهورية الجزائرية الديمقراطية الشعبية (Arabic) République algérienne démocratique et populaire (Faransé) | |
---|---|
Motto: بالشّعب وللشّعب ("By the people and for the people") | |
Ibùdó ilẹ̀ Àlgéríà (dark green) | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Algiers 36°42′N 3°13′E / 36.700°N 3.217°E |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Arabic • Berber |
Other languages | French (administration, business and education) Algerian Arabic (Darja) (lingua franca) |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn |
|
Ẹ̀sìn |
|
Orúkọ aráàlú | Algerian |
Ìjọba | Unitary semi-presidential constitutional republic |
Abdelmadjid Tebboune | |
• Prime Minister | Nadir Larbaoui |
• Council Speaker | Salah Goudjil |
• Assembly Speaker | Slimane Chenine |
Aṣòfin | Parliament |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | Council of the Nation |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | People's National Assembly |
Formation | |
• Zayyanid dynasty | 1235 |
• Al Jazâ'ir | 1515 |
• French Occupation | 5 July 1830 |
• Independence from France | 3 July 1962 |
• Recognised | 5 July 1962 |
• Current constitution | 10 September 1963 |
Ìtóbi | |
• Total | 2,381,741 km2 (919,595 sq mi) (10th) |
• Omi (%) | 1.1 |
Alábùgbé | |
• 2020 estimate | 43,600,000 (32nd) |
• Ìdìmọ́ra | 17.7/km2 (45.8/sq mi) (168) |
GDP (PPP) | 2019 estimate |
• Total | ▲ $684.649 billion (35th) |
• Per capita | ▲ $15,765 (82nd) |
GDP (nominal) | 2019 estimate |
• Total | ▲ $180.687 billion (53rd) |
• Per capita | ▲ $4,229 (109th) |
Gini (2011) | 27.6 low |
HDI (2018) | ▲ 0.759 high · 82nd |
Owóníná | Dinar (DZD) |
Ibi àkókò | UTC+1 (CET) |
Irú ọjọ́ọdún | dd/mm/yyyy |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | +213 |
ISO 3166 code | DZ |
Internet TLD | .dz الجزائر. |
Àlgéríà i bode ni ariwailaorun mo pelu Tùnísíà, ni ilaorun pelu Libya, ni iwoorun pelu Moroko, ni guusuiwoorun pelu Apaiwoorun Sahara, Mauritania, ati Mali, ni guusuilaorun pelu Niger, ati ni ariwa pelu Okun Mediterraneani Sea. Titobi re fe je 2,400,000 square kilometres (930,000 sq mi), be si ni iye awon eniyan re je 35,700,000 ni January 2010. The capital of Algeria is Algiers.
Àlgéríà je omo egbe Iparapo awon Orile-ede, Isokan Afrika, ati OPEC. Bakanna o tun kopa ninu dida ikoenu owo Isokan Maghreb.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Àlgéríà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.