Àgbàdo (Látìnì: Zea mays) ni ó jẹ́ óuńjẹ jij́ẹ oní hóró tí àwọn ènìyàn ilẹ̀ apá Gúúsù ilẹ̀ Mexico ṣe àwárí rẹ̀ ní ǹkan bíi egberun mewa odun seýin..
Igi àgbàdo ma ń yọ ewé sooro, tí ó sì ma ń yọ ìrùkẹ̀rẹ̀ ní ọwọ́ òkè èyí tí ó ma ń ṣe atọ́nà fún yíyọ ọmọ àgbàdo . Àwọn onímọ̀ sáyẹ́nsì fẹ́ràn láti máa pèé ní Maize (àgbàdo) nítorí wípé orúkọ yí ni ó gbajúmọ̀ jùlọ fún irúfẹ Oúnjẹ oníhóró yí, tí ó sì ní it̀umọ̀ oríṣiríṣi lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn ní orílẹ̀ àgbáyé.
Àgbàdo | |
---|---|
Illustration showing male and female maize flowers | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Ìjọba: | Ọ̀gbìn |
Clade: | Vascular plant |
Clade: | Flowering plant |
Clade: | Monocotyledon |
Clade: | Commelinids |
Ìtò: | Poales |
Ìdílé: | Poaceae |
Ìbátan: | Zea (plant) |
Irú: | Z. mays |
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Zea mays |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Àgbàdo, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.