Roald Engelbregt Gravning Amundsen (Àdàkọ:IPA-sv; 16 July 1872 – c.
18 June 1928) je oniwakiri ara Norway. ọmọ ọdún márùn dín ní ọgọ́ta ni. Ẹni àkọ́kọ́ tí ó dé póólù gúsù. Ó ṣe alábápàdá ikú rẹ̀ ní ibi ìjàmbá ọkọ̀ òfurufú ní odò bárẹ́ǹtì. Àwon òbí rẹ ni Jen Amundsen àti Hanna Sahlqvist. Ó gba àmì ẹ̀yẹ Úbádì ní ọdún 1907 láti ọwọ àwọn Ẹgbẹ arin ìrìn àjò aláwárí fún eni àkókó tí ó ṣe àwárí agbègbè Àríwá ìlà oòrùn. Kò gbè ìyàwó, bẹ́ẹ́ní kò sì bí omo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Roald Amundsen, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.