Tsẹ́kì Olómìnira (Tsẹ́kíà; pípè /ˈtʃɛk/ ( listen) chek; Tsẹ́kì: error: }: text has italic markup (help), Àdàkọ:IPA-cs, short form Česko Àdàkọ:IPA-cs) je orile-ede ni Arin Europe.
O ni bode mo Poland ni ariwailaorun, Jemani ni iwoorun ati ariwaiwoorun, Austria ni guusu ati Slovakia ni ilaorun. Orile-ede Tseki Olominira ti je omo egbe NATO lati 1999 ati Isokan Europe lati 2004. Bakanna o tun je omo egbe Agbajo fun Abo ati Ifowosowopo ni Europe (OSCE).
Tsẹ́kì Olómìnira Czech Republic Česká republika | |
---|---|
Orin ìyìn: [Kde domov můj?] error: {{lang}}: text has italic markup (help) (Czech) "Where is my home?" | |
Ibùdó ilẹ̀ Tsẹ́kì Olómìnira (green) – on the European continent (light green & grey) | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Prague (Praha) |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Czech Recognized minority languages: Slovak, Polish, German, Romani |
Orúkọ aráàlú | Czech |
Ìjọba | Parliamentary republic |
• President | Miloš Zeman |
• Prime Minister | Petr Fiala |
Formation | |
• Principality of Bohemia | c. 870 |
28 October 1918 | |
• Czech Republic | 1 January 1993 |
Ìtóbi | |
• Total | 78,871 km2 (30,452 sq mi) (115th) |
• Omi (%) | 2.12 (as of 2020) |
Alábùgbé | |
• 2021 estimate | 10,701,777 (86th) |
• 2011 census | 10,436,560 |
• Ìdìmọ́ra | 136/km2 (352.2/sq mi) (62th) |
GDP (PPP) | 2020 estimate |
• Total | ▲ $432.346 billion (36th) |
• Per capita | ▲ $40,585 (34th) |
GDP (nominal) | 2020 estimate |
• Total | ▲ $261.732 billion (36th) |
• Per capita | ▲ $24,569 (37th) |
Gini (2019) | 24.0 low · 5th |
HDI (2019) | ▲ 0.900 very high · 27th |
Owóníná | Czech koruna (CZK) |
Ibi àkókò | UTC+1 (CET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+2 (CEST) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | +4204 |
Internet TLD | .cz³ |
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Tsẹ́kì Olómìnira, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.