Mọ́skò

Mọsko ni olú-ìlú Rọ́síà.

Ìlú nlá ni. Orí odò Moskva ni ó wà. Odún 1918 ni ó di olú-ìlú USSR nígbà tí wón gbé olú-ìlú yìí kúrò ní Leningrad. Moscow ni ìlú tí ó tóbi jù ní Rósíà. Oun ni ó wà ní ipò kefà tí a bá ní kí á ka àwon ìlú tí ó tóbi ní ilé-ayé. Ìlú tí ó léwà ni Moscow. Uspenki Cathedral tí ó wà ní ibè ni wón ti máa n dé àwon tsar (àwon olùdarí Rósíà) lade láyé àtijó. Ibè náà ni Arkhangelski tí wón ti n sin wón wà. Ilé-isé àti Ilé-èko pò ní ibè Lára àwon ilé-èkó ibè ni. Lomonosov University tí ó jé University ìjoba wa ni ibe. Orí òkè Lenin ni wón kó o sí òun sì ni University tí ó tóbi jù ní Rósíà. Ibè náà ni USSR Academy of Sciences wa. Mùsíómù, ilé-ìkàwé àti tíátà wà níbè. Àwon Bolshoi Theatre and Ballet, the State Symphony Ochestra àti the State Folk Dance Company tí ó wà ni Moscow gbayì gan-an ni.

Mọsko
Red Square
Red Square
Area
 • Total1,081 km2 (417 sq mi)
Population
 • Total12,382,754





Itokasi

Tags:

Rọ́síà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

BhùtánPaul OmuAnnona squamosae21 AprilAdvanced Audio CodingBeirutDe factoÌjà fẹ́tọ̀ọ́ ObìnrinDmitry MedvedevUgandaSony12 MaySan FranciscoGúúsù ÁfríkàPonun StelinAAmẹ́ríkàn futbọ́ọ̀lùÌsọ̀kan Sófìẹ̀tìISBNAgaricocrinusÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1924RembrandtÒmìniraÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Èdè LárúbáwáVictoria University of ManchesterÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÀtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè Olómìnira àgbáyéÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1956Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kanJay-ZẸ̀sìn KrístìHTMLÀkàyéOjúọ̀run ayéMediaWikiÙsbẹ̀kìstánShepseskafÌtàn àkọọ́lẹ̀ YorùbáAma Ata Aidoo16 FebruaryÀṣà Yorùbá.dj12 June12 DecemberMẹ́tàlì21 December13 November.nzIrinNamibiaỌ̀rúndún 21kIfáIṣẹ́ ọnà13 AprilUSAEurope29 FebruaryAustrálíàIlorinHamburgTóyìn AbrahamInternet Relay ChatWiki Commons🡆 More