Assyria

Assyria ni ile-oba to gbale si Oke odo Tigris, ni Mesopotamia (Iraq), to joba lori awon opo ile obaluaye lopo igba.

Oruko re wa lati oruko oluilu re akoko eyun ilu ayeijoun Assur (Akkadian: [𒀸𒋗𒁺 𐎹 Aššūrāyu] error: {{lang}}: text has italic markup (help); Arabiki: أشور [Aššûr] error: {{lang}}: unrecognized language tag: arLatn (help); Heberu: אַשּׁוּר Aššûr, Aramaic: ܐܫܘܪ Ašur. Bakanna Assyria tun le je agbegbe jeografi tabi inu ibi ti awon ile obaluaye wonyi wa.

Assyria
Map of the Neo-Assyrian Empire and its expansions.
Ancient
Mesopotamia
Euphrates · Tigris
Sumer
Eridu · Kish · Uruk · Ur
Lagash · Nippur · Ngirsu
Elam
Susa · Anshan
Akkadian Empire
Akkad · Mari
Amorites
Isin · Larsa
Babylonia
Babylon · Chaldea
Assyria
Assur · Nimrud
Dur-Sharrukin · Nineveh
Hittites · Kassites
Ararat / Mitanni
Chronology
Mesopotamia
Sumer (king list)
Kings of Elam
Kings of Assyria
Kings of Babylon
Mythology
Enûma Elish · Gilgamesh
Assyrian religion
Language
Sumerian · Elamite
Akkadian · Aramaic
Hurrian · Hittite

Nigba Assyria Atijo (awon orundun 20th de 15th BCE), Assur joba lori opo Mesopotamia Loke ati awon apa Asia Minor. Nigba Asiko Arin Assyria (awon orundun 15th de 10th BCE), ipa re resile gidigidi sugbon o fi ija gba won pada. Ile Obaluaye Assyria Tuntun ti Igba Ibere Irin (911 – 612 BCE) fe si gidigidi, be sini labe Ashurbanipal (r. 668 – 627 BCE) fun awon odun ewa o joba lori Ayipo Olora, ati Egypt, ko to bo sowo Babiloni Tuntun ati Medes ki awon eleyi na o to bo sowo Ile Obaluaye Persia.

Itokasi

Tags:

Arabic languageAramaic languageHebrew languageIraq

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ISO 11992ISBNISO 15897Lalisa ManobalNational Basketball AssociationISO/IEC 11801TwitterISO 8000ISO 18245Àjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020Common CriteriaISO 14644-6ÀlgéríàISO 22000Deutschlandlied.iqISO 6344ISO/IEC 17024Pópù Jòhánù 17kÒrìṣà EgúngúnNaira MarleyIonuț Silaghi de OasAfeez OwóISO 10006Bíbélì Mímọ́ISO 14644-5Albert EinsteinAbrahamuNigerian People's PartyYemenNashvilleÀdírẹ́ẹ̀sì IPBahiaQ27 NovemberRihannaIslàmabadISO 9529918 IthaOffice Open XMLOggOrílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ KóngòEdward Adelbert DoisyKọ́nsónántì èdè YorùbáISO 14644-2ISO 11170ISO 5776Táyọ̀ Awótúsìn.tgISO/IEC 17025TapiocaIfáISO 4Charles Glover BarklaFederalismTunisiaỌbàtáláẸ̀bùn GrammyVÀdìtú OlódùmarèFrederik Willem de KlerkLitas.ttÀṣàISO 1413NílòAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ IpokiaISO/IEC 27005National Basketball League (United States)ISO 3103WikiOpenDocumentOrílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin Áfríkà🡆 More