Ọ̀rọ̀ayéijọ́un (Archaeology, tabi archeology lede Geesi lati ede Griiki ἀρχαιολογία, archaiologia – ἀρχαῖος, arkhaios, ayeijoun; and -λογία, -logia, -logy) je agbeka awujo omoniyan, lakoko nipa iwari ati ituyewo asa ohun-ini ati awon data ayika ti won fi seyin, ti ninu won je iseowo, onaikole, onidajuayika ati ojuile asa (eyun akoole oloroayeijoun).
Nitoripe oroayeijoun lo orisirisi igbese otooto, o se e gba bi sayensi ati bi awon eko omoniyan, be sini ni Amerika won gba bi eka oroomoniyan, botilejepe ni Europe won gba bi eka-eko to dawa.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ọ̀rọ̀ayéijọ́un, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.