Ninu Ìmọ̀ Ìṣirò nọ́mbà àkọ́kọ́ (prime numbers) ni a si àwọn nomba adabaye (natural numbers) tí wọn ní nọmba ádábá méjí péreé tí a lè fí pín wọn dọ́gba, éyí ní nọmbaa 1 atí nọmba ákọkọ fún árá rẹ.
Áwọn nọmba ákọkọ pọ tó bẹẹ tó fí jẹ wípé wọn kò lòpin gẹgẹe bí Efklidi ṣé fihàn ní ọdúnn 300 K.J (kia to bi Jesu, K.J). Nọmba ódò 0 ati ọ̀kan 1 kì ṣé nọmba akọkọ.
Àwọn nọ́mbà nínú ìmọ̀ mathematiki |
---|
Basic |
Nọ́mbà àdábáyé |
Complex extensions |
Quaternions |
Other extensions |
Musean hypernumbers |
Other |
Nominal numbers |
Bí àwọnon nọmba akọkọ ṣé
ẹètárá wọn wí íi yi : 2, 3, 5, 7, 11, 13, 17, 19, 23, 29, 31, 37, 41, 43, 47, 53, 59, 61, 67, 71, 73, 79, 83, 89, 97, 101, 103, 107, àtí, and 113
Nọmba 2 (íkèji)
í
i
íó
ẹ
ọIpóleùse ẹAbagbo Isesiro la kale pe gbogbo nọ́mbà odidi (integers) apa otun ti won tobi ju 1 lo se ko sile gege bi isodipupo nomba akoko kan tabi jubelo ni ona kan pato. Fun apere a le ko:
Awon nomba akoko ko ni ye. Eyi ti je fifihan lopolopo ona. Eni akoko to koko fi eyi han ni Efklidi. Bi o se fi han ni yi:
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Nọ́mbà àkọ́kọ́, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.